Moji Afolayan: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Content deleted Content added
No edit summary
Àwọn àlẹ̀mọ́: Àtúnṣe ojú fóónù Àtúnṣe ojú fóónù Advanced mobile edit
No edit summary
Àwọn àlẹ̀mọ́: Àtúnṣe ojú fóónù Àtúnṣe ojú fóónù Advanced mobile edit
Ìlà 23:
}}
 
'''{{PAGENAME}}Mojí Afọláyan''' tí wọ́n bí ní Ọjọ́ karùn-ún oṣù kejì ọdún 1969 (February 5, 1969) jẹ́ gbajúmọ̀ òṣèrébìnrin, olóòtú àti olùdarí sinimá-àgbéléwò ọmọ bíbí [[Yorùbá]] láti ìlú Ìbàdàn lórílẹ̀-èdè [[Nàìjíríà]].<ref>{{cite web|url=http://www.thenationonlineng.net/2011/index.php/mobile/sunday-magazine/screen/59833-why-my-husband-stays-at-home-to-nurse-the-kids—moji-afolayan.html|title=Why my husband stays at home to nurse the kids-Moji Afolayan|work=The Nation Newspaper|accessdate=27 February 2015}}</ref> Mojí jẹ́ ọ̀kan lára àwọn ọmọ bíbí olóògbé òní-sinimá àgbéléwò [[Ade Love|Adéyẹmí Josiah Afọláyan]]<ref name="The Punch - Nigerias Most Widely Read Newspaper 2015">{{cite web | title=Dad didn’t encourage his children to act —Kunle Afolayan | website=The Punch - Nigeria's Most Widely Read Newspaper | date=2015-02-28 | url=http://www.punchng.com/feature/famous-parents/dad-didnt-encourage-his-children-to-act-kunle-afolayan/ | archive-url=https://web.archive.org/web/20150228154441/http://www.punchng.com/feature/famous-parents/dad-didnt-encourage-his-children-to-act-kunle-afolayan/ | archive-date=2015-02-28 | url-status=dead | access-date=2019-12-31}}</ref> tí gbogbo ènìyàn mọ̀ sí [[Ade Love]] nígbà ayé rẹ̀. Mojí Afọláyan fẹ́ gbajúgbajà òṣèré sinimá àgbéléwò, [[Òjòpagogo|Razaq Ọláyíwọlá]] tí gbogbo ènìyàn mọ̀ sí [[Òjòpagogo]]. <ref name="The Nation Newspaper 2018">{{cite web | title=Latest Nigeria news update | website=The Nation Newspaper | date=2018-09-03 | url=https://thenationonlineng.net/ | language=la | access-date=2019-12-31}}</ref>
 
==Àwọn Ìtọ́kasí==