Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò "Ọ̀jọ̀gbọ́n Ayọ̀ Akínwálé"

(Ẹ̀ka; fix red category)
 
Ọ̀jọ̀gbọ́n '''Ayọ̀ Akínwálé''' jẹ́ òṣèré orí-ìtàgé àti sinimá àgbéléwò, olùgbéré jáde ati Olùkọ́ àgbà fásitì.
==Ìgbésí ayé ati ẹ̀kọ́ rẹ̀==
Wọ́n bí Akínwálé ní Ìlú [[Ìbàdàn]], ó lọ sí ilé-ẹ̀kọ́ oníwé mẹ́wàá ti Methodist High School àti [[YunifásitìYunifásítì Ìlúìlú Ìbàdàn]]. Ó ṣiṣẹ́ gẹ́gẹ́ bí olùkọ́ àgbà ní ilé-ẹ̀kọ́ gbogbonìṣe ti ìlú Ìbàdàn.<ref name=dawn>{{cite web|url=http://dawncommission.org/professor-ayo-akinwale/|website=Dawn Commission|title=Professor Ayo Akinwale|accessdate=August 29, 2015}}</ref> Ó tún jẹ́ adarí ẹ̀ka ètò-ẹ̀kọ́ ti Faculty of Arts and Culture ní [[University of Ilorin]].<ref>{{cite web|url=http://www.thisdaylive.com/articles/don-tasks-nollywood-on-professionalism/156624/ |archive-url=https://archive.is/20141115213943/http://www.thisdaylive.com/articles/don-tasks-nollywood-on-professionalism/156624/ |url-status=dead |archive-date=15 November 2014 |title=Don Tasks Nollywood on Professionalism |publisher=thisdaylive.com |accessdate=15 November 2014 }}</ref><ref>{{cite web | url=http://www.modernghana.com/movie/437/3/lecturers-as-nollywood-stars.html | title=Lecturers as Nollywood Stars | publisher=modernghana.com | accessdate=15 November 2014}}</ref> Ọ̀jọgbọ́n Akínwálé nígbà ayé rẹ̀ tún jẹ́ alága fún ìgbìmọ̀ àwọn oníṣẹ́-ọnà (Council for Artand Culture) ti [[Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́]]. Bákan náà ni ó ti ṣe àgbéyẹ̀wò àwọn eré ọdún ìbílẹ̀ oríṣiríṣi ní orílẹ̀-èdè [[Nàìjíríà]].
Ó bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ eré ìtàgé rẹ̀ ní ọdún 1970s níbi tí ó kópa ní àwọn eré sinimá orí ẹ̀rọ amóhù-máwòrán àti àwọn eré ìtagé mìíràn.<ref name=dawn/> Ó ti gba àmì ẹ̀yẹ ìdánọ́lá ti [[4th Africa Movie Academy Awards]] ẹlẹ́kẹrin irú rẹ̀ níbi tí wọ́n ti yàán gẹ́gẹ́ bí òṣèré orí-ìtàgé ọkùnrin tí ó peregedé jùlọ..<ref>{{cite web|url=http://www.thisdaylive.com/articles/between-film-and-professionalism/157244/ |archive-url=https://archive.is/20141115213942/http://www.thisdaylive.com/articles/between-film-and-professionalism/157244/ |url-status=dead |archive-date=15 November 2014 |title=Between Film And Professionalism |publisher=thisdaylive.com |accessdate=15 November 2014 }}</ref>
 
==Àwọn sinimá tí ó ti ṣe==