Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò "Flora Shaw"

2 bytes added ,  10:30, 7 Oṣù Kẹ̀wá 2020
 
 
==Iṣẹ́ rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí oníṣẹ́ ìròyìn==
Ó bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ rẹ̀ tí yàn láàyò ní ọdún 1886, nígbá tí ó kọ ìròyìn fún ilé-iṣẹ́ ìròyìn ''[[Pall Mall Gazette]]'' ati ''[[Manchester Guardian]]''.<ref name="NPGLugard">{{cite web|title=Flora (née Shaw), Lady Lugard (1852-1929), Author and journalist; wife of Frederick Lugard, 1st Baron Lugard|url=http://www.npg.org.uk/collections/search/person.php?LinkID=mp65594|website=National Portrait Gallery|accessdate=11 October 2014}}</ref> Òun ni ilé-iṣẹ́ [[Ìwé-ìròyìn]] ti ''[[Manchester Guardian]]'' rán lọ láti lọ kó àwọn ìròyìn kan jọ nípa àpérò tí ó fẹ́ wáyé ní orí awuye-wuye ìkorò ojú sí àti fífagi lé òwò-ẹrù tí ó fẹ́ wáyé ní [[Brussels]]. Lẹ́yìn iṣẹ́ yí, ó di ògbóntagì ònkọ̀ròyìn lórí "Ìmúnisì" fú ilé-iṣẹ́ ''[[The Times]]'', èyí sì ni ó mu di [[obìnrin]] àkọ́kọ́ tí ó jẹ́ ònkọ̀wé ìròyìn tí ó ń gba [[owó]] gidi jùlọ lásìkò náà. <ref name="NPGLugard"/><ref name="Meyer"/> Fúndí èyí, wọ́n ran ní iṣẹ́ pàtàkì kan tí ó jẹ́ iṣẹ́ àkanse sí apá Ìla Oòrùn [[Áfíríkà]] ní ọdún 1892 àti 1901. [[South Africa]] ní ọdún 1892 orílẹ̀-èdè [[AustrailiaAustrálíà]] ní ọdún 1901, [[New Zealand]] ní ọdún 1892,láti kọ́ nípa ohun tí ó ń lọ ní [[Kanakas|Kanaka]] tí àwọn òṣìṣẹ́ ti ń ṣíṣe nínú [[oko]] [[ìrèké]] ní [[Queensland]]. Ìlú [[Penneshaw, South Australia]] ni wọ́n fi díẹ̀ lára orúkọ ìlú náà sorí Flora.<ref>[[Rodney Cockburn]] (1908) ''What's in a name? Nomenclature of South Australia'': Fergusson Publications {{ISBN|0-9592519-1-X}}</ref>
Ón tún kọ àwọn ìròyìn ọlọ́kan-ò-jọkan nípa ìlú [[Canada]] ní ọdún 1893 àti 1898. Ó tún kọ nípa ìwakùsà [[góòlù]] ní [[Klondike Gold Rush|Klondike]].<ref name=HistoryToday>{{cite journal|last1=Usherwood|first1=Stephen|title=From Our Own Correspondent: Flora Shaw on the Klondike|journal=History Today|url=http://www.historytoday.com/stephen-usherwood/our-own-correspondent-flora-shaw-klondike|accessdate=12 October 2014}}</ref><ref name="EB1922">{{Cite EB1922|wstitle=Lugard, Sir Frederick John Dealtry}}</ref>