Àdàkọ:Ayoka Ose/8: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Content deleted Content added
No edit summary
Àlẹ̀mọ́: Reverted
No edit summary
Àlẹ̀mọ́: Manual revert
Ìlà 1:
[[File:Genevieve30.jpg|100px|left|Genevieve Nnaji ní ọjọ́ tó sí ilé ìránso St.Genevieve rẹ̀ ní Èkó, Nàìjíríà, May 2008]]
[[File:Social distancing queueing for the supermarket J. Sainsbury's north London Coronavirus Covid 19 pandemic - 30 March 2020.jpg|thumb|upright=1.5|Àwọn ènìyàn tí wọ́n ń ṣe àmúlò Ìjìnnà-síra-ẹni nípa títò lọ́wọọ̀wọ́ láti wọnú ọjà ìgbàlódé ní ìlú London nígbà àjàkálẹ̀ ààrùn [[èrànkòrónà]] lọ́dún 2020 [[COVID-19 pandemic]]]]
'''[[Genevieve Nnaji]]''' jẹ́ òṣeré filmu ọmọ ilẹ̀ [[Nàìjíríà]]. Ní 2005 ó gba Ẹ̀bùn Akadẹ́mì Filmu ilẹ̀ Áfríkà gẹ́gẹ́ bíi Òṣeré Obìnrin Dídárajùlọ. Ìlú [[Èkó]] ni Genevieve Nnaji ti dàgbà. Ìkẹrin nínú àwọn ọmọ méjọ, ọ̀mọ̀wé ni àwọn òbí rẹ̀. Bàbá rẹ̀ siṣẹ́ gẹ́gẹ́ bíi onímọ̀ iṣẹ́-ẹ̀rọ (engineer) nígbàtí ìyá rẹ̀ sì jẹ́ olùkọ́. Ò lọ sí ilé ẹ̀kọ́ Methodist Girls College ní [[Yaba]], lẹ́yìn rẹ̀ ó tẹrísí [[Yunifásítì ìlú Èkó]]. Níbẹ̀ lówà tó ti bẹ̀rẹ̀ sí ní ṣiṣẹ́ díèdíẹ̀ gẹ́gẹ́ bíi òṣèré ni [[Nollywood]]. Nnaji bẹ̀rẹ̀ ìṣèré rẹ̀ láti ọmọdé ninu eré tẹlifísọ̀n ''Ripples'' nígbà tójẹ́ ọmọ ọdún 8. Ó tún ṣe ìpolówó ọjà bíi méèló kan nínú èyí tó jẹ́ fún Pronto àti ọṣẹ ìfọsọ OMO. Ní 2004 ó di aṣojú fún ọsẹ ìwẹ̀ Lux ìbáṣe ìgbọ̀wọ́ tọ́ fa èrè ínlá wá fun. Ni 1998 nígbà tójẹ́ ọmọ ọdún 19 wọn ṣe àmúhàn rẹ̀ sí àwọn olólùfẹ́ filmu ni Naijiria pẹ̀lú filmu tó ún jẹ́ ''Most Wanted''. Lẹ́yìn rẹ̀ ó tún ṣe àwọn filmu bíi ''Last Party, Mark of the Beast'' àti ''Ijele''. Ó ti kópa nínúu filmu tó tó 80 ni Nollywood. Nnaji ti gba ọ̀pọ̀lọpọ̀ ẹ̀bùn fún iṣẹ́ rẹ̀ ìkan nínú wọn jẹ́ gẹ́gẹ́ bíi òṣèré obìnrin tódárajùlọ fún 2001 ní City People Awards, ó sì tún gba ẹ̀yẹ gẹ́gẹ́ bíi Òṣèré Obìnrin tó dára jùlọ ní 2005 nínú àwọn Ẹ̀bùn Akadẹ́mì Filmu ilẹ̀ [[Áfríkà]].
[[File:Covid-19-Transmission-graphic-01.gif|thumb|upright=1.5|Ìjìnnà-síra-ẹni láwùjọ máa ń ṣe àdínkù àti ìdálọ́wọ́kọ́ àjàkálẹ̀ ààrùn láwùjọ.]]
([[Genevieve Nnaji|ìtẹ̀síwájú...]])'''
Nínú ètò ìlera àwùjọ, '''[[Ìjìnnà-síra-ẹni láwùjọ]]''' ('''Ìjìnnà-síra-ẹni lójúkojú'''),<ref name="WHO_20200320">{{cite web |title=COVID-19 |author-first1=Margaret |author-last1=Harris |author-first2=Tedros |author-last2=Adhanom Ghebreyesus |author-link2=Tedros Adhanom Ghebreyesus |author-first3=Tu |author-last3=Liu |author-first4=Michael "Mike" J. |author-last4=Ryan |author-link4=Michael J. Ryan (doctor) |author5=Vadia<!-- Nowruz, Iran --> |author-first6=Maria D. |author-last6=Van Kerkhove |author-link6=Maria D. Van Kerkhove |author7=Diego<!-- Vortex --> |author-first8=Imogen |author-last8=Foulkes |author-first9=Charles |author-last9=Ondelam |author-first10=Corinne |author-last10=Gretler |author11=Costas<!-- ERT, Greece --> |date=20 March 2020 |publisher=[[World Health Organization]] |url=https://www.who.int/docs/default-source/coronaviruse/transcripts/who-audio-emergencies-coronavirus-press-conference-full-20mar2020.pdf?sfvrsn=1eafbff_0 |access-date=29 March 2020 |url-status=live |archive-url=https://web.archive.org/web/20200325084602/https://www.who.int/docs/default-source/coronaviruse/transcripts/who-audio-emergencies-coronavirus-press-conference-full-20mar2020.pdf?sfvrsn=1eafbff_0 |archive-date=25 March 2020}}</ref><ref name="Hensley_20200323">{{cite web |author-first=Laura |author-last=Hensley |title=Social distancing is out, physical distancing is in – here's how to do it |work=[[Global News]] |date=23 March 2020 |publisher=[[Corus Entertainment Inc.]] |url=https://globalnews.ca/news/6717166/what-is-physical-distancing/ |access-date=29 March 2020 |url-status=live |archive-url=https://web.archive.org/web/20200326180136/https://globalnews.ca/news/6717166/what-is-physical-distancing/ |archive-date=27 March 2020}}</ref><ref name="Venske_20200326">{{cite web |title=Die Wirkung von Sprache in Krisenzeiten |language=de |trans-title=The effect of language in times of crisis |date=26 March 2020 |editor-first=Andrea |editor-last=Schwyzer |author-first=Regula |author-last=Venske |author-link=:de:Regula Venske |type=Interview |publisher=[[Norddeutscher Rundfunk]] |series=NDR Kultur |url=https://www.ndr.de/kultur/Corona-Die-Wirkung-von-Sprache-in-Krisenzeiten,venske118.html |access-date=27 March 2020 |url-status=live |archive-url=https://web.archive.org/web/20200327214038/https://www.ndr.de/kultur/Corona-Die-Wirkung-von-Sprache-in-Krisenzeiten,venske118.html |archive-date=27 March 2020}} (NB. Regula Venske is president of the [[PEN Centre Germany]].)</ref> jẹ́ ìlànà tí kìí ṣe nípa ìmọ̀ ìjìnlẹ̀ ìlò oògùn pẹ̀lú èròǹgbà láti dènà títànká àjàkálẹ̀ ààrùn nípa jíjìnnà sí ara ẹni lójúkojú láti ṣe àdínkù iye ìgbà tí àwọn ènìyàn lè súnmọ́ ara wọn pẹ́kípẹ́kí.<ref name="WHO_20200320"/><ref name="JohnsonSunFreedman 2020">{{Cite news |author-last1=Johnson |author-first1=Carolyn Y. |author-last2=Sun |author-first2=Lena |author-last3=Freedman |author-first3=Andrew |title=Social distancing could buy U.S. valuable time against coronavirus |newspaper=[[The Washington Post]] |date=10 March 2020 |url=https://www.washingtonpost.com/health/2020/03/10/social-distancing-coronavirus/ |access-date=11 March 2020 |url-status=live|archive-url=https://web.archive.org/web/20200327163232/https://www.washingtonpost.com/health/2020/03/10/social-distancing-coronavirus/ |archive-date=27 March 2020}}</ref> Ó jẹ mọ́ ìṣèdiwọ̀n bí ènìyàn kan ṣe lè jìnnà sí ẹlòmíràn (irú òdiwọ̀n bẹ́ẹ̀ máa ń yàtọ̀ láti ìgbà dé ìgbà àti ní orílẹ̀ èdè kọ̀ọ̀kan) àti yíyẹra fún ìpéjọpọ̀ ọ̀pọ̀ èèyàn.<ref name="Pearce2020"/><ref name="CDC22March2020"/>
 
 
([[Ìjìnnà-síra-ẹni láwùjọ|Ìjìnnà-síra-ẹni láwùjọ...]])'''