Fòpin sí SARS: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Content deleted Content added
kNo edit summary
Ìlà 14:
==Bí ó ṣe bẹ̀rẹ̀==
Ìfẹ̀hónúhàn náà bẹ̀rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí ìpolongo lórí ìkànnì ayélujára Twitter pẹ̀lú àrokò #ENDSARS láti sọ fún [[Ìjọba Àpapọ̀ Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà]] láti fòpin sí àkànṣe ẹ̀ka ọlọ́pàá agbóguntolè, SARS.<ref name=Salaudeen2017>{{cite news |last1=Salaudeen |first1=Aisha |title=Nigerians want police's SARS force scrapped |url=http://www.aljazeera.com/news/2017/12/nigerians-demand-police-sars-unit-171215153831230.html |accessdate=2 January 2018 |publisher=Aljazeera |date=15 December 2017 |df=dmy-all}}</ref><ref>{{cite news |title=End SARS as a Mob Project |url=https://www.thisdaylive.com/index.php/2017/12/17/end-sars-as-a-mob-project/ |accessdate=2 January 2018 |publisher=Thisday Newspapers Limited |place=Nigeria |date=17 December 2017 |df=dmy-all}}</ref><ref>{{cite news |last1=Ogundipe |first1=Samuel |title=#EndSARS: Police mum as Nigerians recount atrocities of Special Anti-Robbery Squad |url=https://www.premiumtimesng.com/news/headlines/251271-endsars-police-mum-nigerians-recount-atrocities-special-anti-robbery-squad.html |accessdate=2 January 2018 |publisher=Premium Times |place=Nigeria |date=December 3, 2017 |df=dmy-all}}</ref> Láàárín òpin ọ̀sẹ̀ kan, lọ́jọ́ kẹsàn-án sí kọkànlá oṣù kẹwàá ọdún 2020, (9–11 October 2020), àrokò #ENDSARS ti ní ìpolongo mílíọ̀nù méjìdínlọ́gbọ̀n lórí Twitter.<ref>{{Cite web|last=Kazeem|first=Yomi|title=How a youth-led digital movement is driving Nigeria's largest protests in a decade|url=https://qz.com/africa/1916319/how-nigerians-use-social-media-to-organize-endsars-protests/|access-date=2020-10-13|website=Quartz Africa|language=en}}</ref> Lásìkò yìí, àwọn ọmọ Nàìjíríà ṣe àfihàn àwọn ẹ̀rí àwòrán àti fídíò ìwà àìbófinmu bíi: '''jíjínigbé''', '''ìpànìyàn''', '''ìfipábánilò'''', '''olè jíjà''', '''ìfìyàjẹ aláìṣẹ̀ lọ́nà àìtọ́''', '''títi aláìṣẹ̀ mọ́lé''', '''pípàyàn lọ́nà''' ÀÌTỌ́àìtọ́ àti '''ìfipágbowó àbẹ̀tẹ́lẹ̀''' tí ẹ̀ka ọlọ́pàá SARS wọ̀nyí ń hù lórílẹ̀-èdè Nàìjíríà. A lè rí àwọn fídíò-bóṣeńlọ lórí ìkànnì ayélujára yìí [http://www.endsars.com Endsars]
 
Wọ́n fẹ̀sùn kan àwọn ọlọ́pàá SARS pé, íṣe ni Wọ́nwọ́n dàmú àwọn aráàlú nípa ṣíṣe àyẹ̀wò ìgbónára àìtọ́ fun aráàlú, jíjínigbé, ìpànìyàn, ìfipábánilòpọ̀, olè jíjà, ìfìyàjẹ aláìṣẹ̀ lọ́nà àìtọ́, títi aláìṣẹ̀ mọ́lé, pípàyàn lọ́nà àìtọ́, ìfipágbowó àbẹ̀tẹ́lẹ̀, híhalẹ̀ àti gbígba owó lọ́wọ́ àwọn ọ̀dọ́ tí wọ́n bá rí nínú ọkọ̀-ayọ́kẹ́lẹ́ bọ̀gìnnì, ìdásílẹ̀ ìbùdó àyẹ̀wò àìtọ́, àyẹ̀wò ẹ̀rọ ìbánisọ̀rọ̀, pàápàá jù lọ iPhones.<ref name=":0">{{Cite web|last=Kazeem|first=Yomi|title=Young Nigerians are leading protests yet again to disband a rogue police unit|url=https://qz.com/africa/1915472/endsars-young-nigerian-protest-rogue-police-unit/|access-date=2020-10-10|website=Quartz Africa|language=en}}</ref> Àwọn kan kéde pé Ìfẹ̀hónúhàn náà tí ṣe àṣeyọrí nígbà tí àwọn aláṣẹ ọlọ́pàá kéde pé wọ́n ti fòpin sí àkànṣe ẹ̀ka ọlọ́pàá SARS lọ́jọ́ kọkànlá oṣù kẹwàá ọdún 2020.<ref>{{Cite web|last=|first=|date=11 October 2020|title=#EndSARS: Nigeria says Special Anti-Robbery Squad dissolved|url=https://www.aljazeera.com/news/2020/10/11/endsars-nigeria-dissolves-special-anti-robbery-squad|url-status=|archive-url=|archive-date=|access-date=11 October 2020|website=Al Jazeera}}</ref> Àwọn mìíràn tako èyí, wọ́n sọ pé ìjọba tí ṣe irú ìlérí bẹ́ẹ̀ rí ṣùgbọ́n tó jásí pàbó, tàbí tó jẹ́ pé pàbó ló jásí. <ref name="Ademoroti">{{cite web |last=Ademoroti |first=Niyi |date=11 October 2020 |title=What It Means When the Police Say They are Dissolving SARS |url=https://www.bellanaija.com/2020/10/what-it-means-when-the-police-say-they-are-dissolving-sars/ |work=BellaNaija |access-date=11 October 2020}}</ref> Ìjọba ti gbìyànjú láti fipá dá Ìfẹ̀hónúhàn náà dúró, ṣùgbọ́n pàbó ni gbogbo ìgbìyànjú wọn ń já sí.<ref name="auto"/>
 
==Àwọn ìtọ́kasí==