Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò "Midé Fúnmi Martins"

k
* -words/*
Àwọn àlẹ̀mọ́: Àtúnṣe ojú fóónù Àtúnṣe ojú fóónù Advanced mobile edit
k (* -words/*)
'''Midé Fúnmi Martins''' (tí a bí ní ọjọ́ Kejìlá oṣù kẹrin ọdún 1979) jẹ́ Òṣeré-bìnrin àti olóòtú sinimá àgbéléwò ọmọ [[Yoruba|Yorùbá]] lórílẹ̀-èdè [[Naijiria|Nàìjíríà]]. Ó jẹ́ ọmọ gbajúgbajà òṣèré-bìnrin olóògbé [[Fúnmi Martin'sMartins]] tó ṣaláìsí lọ́dún 2002. Midé Martins darapọ̀ mọ́ àwọn Òṣeré sinimá àgbéléwò ní kété tí ìyá rẹ di olóògbé. Ó fẹ́ òṣèré, olùdarí àti olóòtú sinimá àgbéléwò tí a mọ sí [[Afeez Owó]].<ref name="Punch Newspapers 2015">{{cite web|title=Friends gave my wife wrong advice to ruin our marriage –Afeez Owo|website=Punch Newspapers|date=2015-12-15|url=https://punchng.com/friends-gave-my-wife-wrong-advice-to-ruin-our-marriage-afeez-owo/|access-date=2019-10-05}}</ref> Ọmọ méjì ni ó bí .<ref name="Informationcradle 2017">{{cite web|title=Mide Martins Bio, Age, Father, Husband Age, Instagram, Movies And More|website=Informationcradle|date=2017-07-25|url=https://informationcradle.com/africa/mide-martins/|access-date=2019-10-05}}</ref>
 
==Àwọn Ìtọ́kasí==