Àdírẹ́ẹ̀sì IP: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Content deleted Content added
No edit summary
No edit summary
Àwọn àlẹ̀mọ́: Reverted Àtúnṣe ojú fóónù Àtúnṣe ojú fóónù
Ìlà 1:
'''Report Spam Àdírẹ́ẹ̀sì Prótókóòlù Íntánẹ́ẹ̀tì''' ('''Àdírẹ́ẹ̀sì IP''') ni àlẹ̀mọ́ ìtò-nọ́mbà tí ó jẹ́ yíyànsílẹ̀ fún ẹ̀rọ kọ̀ọ̀kan tó sopọ̀ mọ́ [[computer network|ẹ̀rọ-àsopọ̀ kọ̀mpútà]] kan tó únlo [[Internet Protocol|Prótókóòlù Íntánẹ́ẹ̀tì]] fún ìbánisọ̀rọ̀.<ref name=rfc760>RFC 760, ''DOD Standard Internet Protocol'', DARPA, Information Sciences Institute (January 1980).</ref><ref name=rfc791>{{Cite IETF|rfc=791|title=Internet Protocol, DARPA Internet Program Protocol Specification|editor=[[Jon Postel|J. Postel]]|date=September 1981|publisher=[[IETF]]}} Updated by {{IETF RFC|1349|2474|6864}}.</ref>
Report Spam Àdírẹ́ẹ̀sì IP kan únṣe ìṣẹ́ mẹ́jì pàtàkì: [[Identification (information)|ìṣe ìdámọ̀]] ẹ̀rọ-agbàlejò tàbí ìfojúkojú ẹ̀rọ-àsopọ̀ àti [[Network address|ìṣe àdírẹ́ẹ̀sì]] ibùdó.
 
[[IPv4|Report Spam Internet Protocol version 4]] (IPv4) ṣe ìtumọ̀ àdírẹ́ẹ̀sì IP kan gẹ́gẹ́ bí nọ́mbà oní [[32-bit]].<ref name=rfc791 /> Sùgbọ́n, nítorí bí Internet ṣe ti tóbi tó àti [[IPv4 address exhaustion|ìdínkù àwọn àdírẹ́ẹ̀sì IPv4 tó wà]], ọ̀nà tuntun mìíràn fún IP ([[IPv6]]), tó ún lo 128 bits fún àdírẹ́ẹ̀sì IP, jẹ́ ṣíṣe àjọhùnsí ní ọdún 1998.<ref name=rfc1883>{{Cite IETF|rfc=1883|title=Internet Protocol, Version 6 (IPv6) Specification|authorlink1=Steve Deering|author1=S. Deering|author2=R. Hinden|date=December 1995|publisher=Network Working Group}}</ref><ref name=rfc2460>{{Cite IETF|rfc=2460|title=Internet Protocol, Version 6 (IPv6) Specification|authorlink1=Steve Deering|author1=S. Deering|author2=R. Hinden|publisher=Network Working Group|date=December 1998}}</ref><ref name=rfc8200>{{Cite IETF|rfc=8200|title=Internet Protocol, Version 6 (IPv6) Specification|authorlink1=Steve Deering|author1=S. Deering|author2=R. Hinden|publisher=[[IETF]]|date=July 2017}}</ref> [[IPv6 deployment|Ìlò IPv6]] ti bẹ̀rẹ̀ láti àrin ìgbà ọdún 2000.
 
Report Spam Àwọn àdírẹ́ẹ̀sì IP ún jẹ́ kíkọ àti híhàn ní ọ̀nà tó ṣe é rí kà fún ọmọ ènìyàn, fún àpẹrẹ, gẹ́gẹ́ bí {{IPaddr|172.16.254.1}} nínú IPv4, àti {{IPaddr|2001:db8:0:1234:0:567:8:1}} nínú IPv6. Ìtóbi ìṣọ̀nà ìfikúnwájú fún àdírẹ́ẹ̀sì jẹ́ yíyànsílẹ̀ nínú [[CIDR notation]] nípa síṣe ìfikúnlẹ́yìn àdírẹ́ẹ̀sì pẹ̀lú nọ́mbà àwọn bit pàtàkì, f.a., {{IPaddr|192.168.1.15|24}}, tó jẹ́ ìkannáà mọ́ subnet mask {{IPaddr|255.255.255.0}} tí wọ́n únlò látì ìbẹ̀rẹ̀.
 
 
{{ẹ̀kúnrẹ́rẹ́}}
==Itokasi==
{{reflist}}
 
[[ẹ̀ka:Àwọn àdírẹ́ẹ̀sì IP]]
[[Ẹ̀ka:internet]]