Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò "Fúnmi Martins"

k
k
 
==Ìbẹ̀rẹ̀ ayé àti ẹ̀kọ́ rẹ̀==
Wọ́n bí Fúnmi ní [[Ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun]] ní inú oṣù Kẹsàn án ọdún 1963, ó lọ sí ilé-ẹ̀kọ́ alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀ Òkè-Ọnà àti ilé-ẹ̀kọ́ girama ní ìlú [[Ìlú Abèọ̀kúta]] ní [[Ìpínlẹ̀ Ògùn]]. Lẹ́yìn ẹ̀kọ́ girama, ó tẹ̀ siwájú nínú ẹ̀kọ́ rẹ̀ ní Beepo Secretarial Institute ní ìlú [[Ìbàdàn]] níbi tí ó ti kẹ́kọ̀ọ́ gba ìwé-ẹ̀rí dípúlọ́mà nínú ìmọ̀ Secretariate.
 
==Iṣẹ́ rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí òṣèré==