Nkhensani Manganyi: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Content deleted Content added
kNo edit summary
Ìlà 3:
== Iṣẹ́ rẹ̀ ==
Ní ọdún 2000, Manganyi bẹ̀rẹ̀ ilé-iṣẹ́ aránṣọ tirẹ̀ tí ó pè ní ''Stoned Cherrie''.<ref name="globe">{{Cite news|url=http://www.boston.com/ae/music/articles/2003/10/14/south_african_protest_songs_find_different_themes/|title=South African Protest Songs Find Different Themes|publisher=[[Boston Globe]]|author=Mariam Jooma|date=2003-10-14}}</ref><ref>{{Cite web|url=http://www.bellanaija.com/2006/08/08/bella-naija-africa-fashion-week-day-1/|title=Africa Fashion Week – Day 1|publisher=[[Bella Naija]]|date=2006-08-08}}</ref> Ìkan lára àwọn aṣọ tí ó rán gbáyi láti ilé iṣẹ́ ìròyìn Drum.<ref>{{Cite news|url=http://www.time.com/time/europe/html/040419/kwaito.html|title=That's Kwaito Style|publisher=[[Time magazine]]|author=Simon Robinson|date=2004-04-11}}</ref>
Ilẹ̀ iṣẹ́ náà má ń ṣe gíláàsì fún [[ojú]]<ref>{{Cite news|url=http://www.news24.com/Archives/City-Press/Winning-Women-Renaissance-fashion-guru-20150430|title=Winning Women: Renaissance fashion guru|work=News24|access-date=2017-03-08}}</ref>. Díè nínú àwọn iṣẹ́ rẹ sì wà ní ''Fashion Institute of Technology'' níbi tí won tí se ìfihàn rẹ níbi ayẹyẹ [[Black Fashion Designers]] ni ọdún 2016<ref>{{Cite news|url=http://nymag.com/thecut/2016/12/black-designers-finally-get-a-museum-exhibit.html|title=Black Designers Finally Get a Museum Exhibit|last=Peoples|first=Lindsay|work=The Cut|access-date=2017-03-08|language=en}}</ref><ref>{{Cite web|url=https://www.fitnyc.edu/museum/exhibitions/black-fashion-designers.php|title=Black Fashion Designers {{!}} Fashion Institute of Technology|website=www.fitnyc.edu|language=en|access-date=2017-03-09}}</ref>.
Manganyi tí kópa nínú àwọn eré bíi ''Legend of the Hidden City'', ''Tarzan:'', ''The Epic Adventures ati Kickboxer 5'' àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ.
Ní ọdún 2003, ó se adájọ́ fún ètò ''Pop Star'' tí won ṣẹ́ lórílẹ̀ èdè [[South Áfríkà]].
 
== Àwọn Ìtọ́kasí ==