Deyemi Okanlawon: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Content deleted Content added
Ṣ'èdá ojúewé pẹ̀lú "{{Infobox person |image = |name = Déyẹmí Ọ̀kánlàwọ́n |imagesize = |caption = |birth_name = Adéyẹmí Ọ̀kánlàwọ́n |b..."
 
Ìlà 19:
Ọ̀kànlàwọ́n bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ eré ṣíṣe nígbà tí ó wà ní ọmọ ọdún márùn-ún níbi tí ó ti kópa nínú eré orí-ìtàgé ìparí ọdun nílé ẹ̀kọ́ alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀.<ref name="Many"/> Nígbà tí ó wà ní ọmọ ọdún mẹsàn án Ó kòpa nínú ìpolówó orí ẹ̀rọ amóhù-máwòrán pẹ̀lú [[Kunle Bamtefa]]. Lásìkò tí ó jẹ́ ọmọ akẹ́kọ̀ọ́ ní ọgbà Yunifásitì [[Ìpínlẹ̀ Èkó]], ó tún dara pọ̀ mọ́ ẹgbẹ́ eléré oníṣẹ́ ti Gf(x) (Harvesters Company), Xtreme Reaction and Snapshots (Covenant Christian Centre).<ref name="Many"/>
 
Òkánlàwọ́n di ìlú-mòọ́ká nípa ip tí ó kó nínú eré ZR-7, ní ọdún 2010. <ref name="Many"/> Ó tún kópa nínú eré ''A Grain of wheat''. Lẹ́yìn èyí, ó tún kópa tí ó sì tún jẹ́ olùgbéré-jáde pẹ̀lú Ìfọwọ́sowọ́pọ̀ àwọn mìíràn láti gbé àwọn eré ọlọ́kan-ò-jọkan jáde. Ní ọdún 2012 ó kópa nínú eré Blink àti Knock Knock ní dédé agogo mẹ́fà àbọ̀ ìrọ̀lẹ́. Ní ọdún 2013, ó dojú kọ eré sinimá nìkan, tí ó sì ti kópa nínú eré tí ó ti tó àádọ́ta lẹ́yìn èyí, tí ó sì tún ti ṣe ìpolongo fún ilé iṣẹ́ ìbára-ẹni-sọ̀rọ̀ [[Globacom]] àti [[OzlX]]. Ó ti bá [[Waje]] àti [[Arámidé]] ṣe fọ́nrán fídíò orin wọn. Ó tún ti kópa nínú eré "Beyond Blood". Ó kòpa nínú eré "If Tomorrow Never Comes" tí [[Joseph Benjamin]] àti Kehinde Bamkole ti kópa. <ref name="Style"/> Ishaya Bako's ''Road To Yesterday'' starring Genevieve Nnaji and Majid Michel and Pascal Amanfo's ''No Man’s Land'' starring Adjetey Anang. He was in [[NdaniTV]]'s series ''[[Gidi Up]]'' with [[OC Ukeje]], [[Titilope Sonuga]], [[Somkele Iyamah]] and [[Joke Silva]].<ref name=ndanitv>[https://www.youtube.com/watch?v=-AiG-1GH9R8 Gidi cast on The Juice], Ndanitv, Retrieved 6 October 2016.</ref> àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ.
 
==Àwọn amì-ẹ̀yẹ rẹ̀==
Ó gba amì-ẹ̀yẹ òṣérékùnrin tó peregedé jùlọ nínú eré kúkúrú nínú '' In-Short film festival'' fún ipa rẹ̀ tí ó kó gẹ́gẹ́ bí " Ọkọ alárùn ọpọlọ" nínú eré ''Blink''.<ref>{{cite web|url=https://ibakatv.com/adeyemi-okanlawon|title=Adeyemi Okanlawon|last=Ibaka|first=TV|date=16 May 2016|work=IbakaTV.com|accessdate=27 June 2016|location=Lagos, Nigeria}}</ref>