Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò "Awa Traoré"

k
Mo ṣàtúnṣe àmì-ọ̀rọ̀
(Added references)
k (Mo ṣàtúnṣe àmì-ọ̀rọ̀)
 
 
== Iṣẹ́ ==
Traoré bẹ̀rẹ̀ eré síse rẹ̀ pẹ̀lú fíímù ''L'enfant noir'' ní ọdún1995. Lẹ́hìnńà ó ṣiṣẹ́ bí ọdẹ ní fíímù ránpẹ́ tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ ''Denko'' èyí tí [[Mohamed Camara]] se adarí rẹ̀ ní ọdún 1993. Fíímù náà gba ìyìn pàtàkì àti àmì ẹ̀yẹ ''Grand Prix'' níbi ayẹyẹ Clermont-Ferrand International Short Film Festival<ref>{{Cite web|last=Nesselson|first=Lisa|title=Clermont-Ferrand Festival of Short Films|publisher=FilmFestivals.com|year=2000|url=http://www.filmfestivals.com/france/overviews/2000/clermont-ferrand_00.htm|accessdate=5 February 2010|archive-url=https://web.archive.org/web/20110604141052/http://www.filmfestivals.com/france/overviews/2000/clermont-ferrand_00.htm#|archive-date=2011-06-04|url-status=dead}}</ref>, ó tún gba ẹ̀bùn fún fíímù ránpẹ́ tí ó dára jùlọ níbi ayẹyẹ Friborg International Film Festival àti àmì ẹ̀yẹ Golden Danzante níbi ayẹyẹ Huesca Film Festival.<ref>{{Cite web|title=37 Huesca International Film Festival|publisher=Huesca Film Festival|year=2009|url=http://www.huesca-filmfestival.com/catalogo/37catalogo/37catalogo/contenidos/7-palmares/pal-en.html|accessdate=5 February 2010|archive-url=https://web.archive.org/web/20100521061923/http://www.huesca-filmfestival.com/catalogo/37catalogo/37catalogo/contenidos/7-palmares/pal-en.html#|archive-date=2010-05-21|url-status=dead}}</ref>
 
== Àṣàyàn àwọn eré rẹ̀ ==