Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò "Àlàdé Arómirẹ́"

k
Kò sí ìsọníṣókí àtúnṣe
(Ṣ'èdá ojúewé pẹ̀lú "'''Muyideen Agboọlá Àlàdé Arómirẹ́''' tí gbogbo ènìyàn tún mọ̀ sí '''Àlàdé Arómirẹ́''' tí wọ́n bí ní Ìpínlẹ̀ Èkó ní...")
 
k
==Iṣẹ́ rẹ̀==
Gẹ́gẹ́ bí òṣèré, ó ti rí gbogbo rògbàdìyàn àti akitiyan tí ó wà nínú lílo ìlànà "atabloid" tí àwọn àgbà òṣèré bíi: [[ Moses Adéjùmọ̀]], Olóyè [[Hubert Ògúndé]] ń lò láti gbé eré jáde tí ó sì ń ná wọn lówó gegere kí eré náà ó tó jáde síta fún àwọn ènìyàn. Ó dá ṣíṣe yíya eré sinimá àgbéléwò àkókọ́ sílẹ̀ tí ó pe àkọọ́lé rẹ̀ ní ''Ẹkùn'' ní ọdún 1989.<ref name="Modern Ghana 2007">{{cite web | title=I STARTED NOLLYWOOD...ALADE AROMIRE | website=Modern Ghana | date=2007-10-01 | url=https://www.modernghana.com/movie/1651/i-started-nollywoodalade-aromire.html | access-date=2020-10-29}}</ref>
 
==Àwọn ìtọ́kasí==
{{reflist}}