Annabella Zwyndila: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Added wiki links and category
Created by translating the page "Annabella Zwyndila"
 
Added wiki links and category
Ìlà 3:
 
== Ìbẹ̀rẹ̀ ayé rẹ̀ àti ẹ̀kọ́ rẹ̀ ==
A bí '''Annabella Zwyndila''' ní [[Ìbàdàn|̀ilú Ìbàdàn]], orílẹ̀-èdè [[Nàìjíríà]]. Bàbá rẹ̀ jẹ́ òṣìṣẹ́ ẹgbẹ́ ọmọ ogun ti Nàìjíríà, ìyá rẹ̀ sì jẹ́ òṣíṣẹ́ àgbà nídi ṣíṣe ètò ẹ̀kọ́ àwọn ará ìlú. Ó lọ sí ilé-ìwé Command Secondary School ní ìlú Jos, [[Ìpínlẹ̀ Plateau]] ṣááju kí ó tó lọ sí [[Yunifásítì ìlú Jos|Yunifásitì ìlú Jos]] níbití ó ti gba oyè ẹ̀kọ́ nínu ìmọ̀ eré ìtàgé ṣíṣe.
 
== Àkójọ àwọn eré tí ó ti kópa ==
Ìlà 60:
[[Ẹ̀ka:Àwọn ènìyàn alààyè]]
[[Ẹ̀ka:Àwọn ọjọ́ìbí ní 1992]]
[[Ẹ̀ka:Àwọn òṣeré ará Nàìjíríà]]
442

edits