Òmuò-Òkè-Èkìtì: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Content deleted Content added
kNo edit summary
kNo edit summary
Ìlà 1:
'''Ìlú Òmùò-Òkè Èkìtì''' jẹ́ ìlú ńlá kan tí ó wà ní apá Ìlà oòrùn Èkìtì ni Òmùò òkè wà. Ìjọba ìbílẹ̀ ìlà Oòrùn ni ìpínlẹ̀ Èkìtì ni Òmùò-òkè tẹ̀dó sí. Òmùò-òkè tó kìlómítà méjìlélọ́gọ́ọ̀rin sí Adó-Èkìtì tí ó jé olú-ìlú ìpínlẹ̀ Èkìtì. Òmùò-òkè ni ìpínlẹ̀ Èkìtì parí sí kí a tó máa- lọ sí ìpìnlẹ̀ Kogi. Ìdí nìyí tí ó fi bá àwọn ìlú bí i, Yàgbà, Ìjùmú, Ìyàmoyè pààlà. Bákan náà ni ó tún bá Erítí Àkókó pààlà ní ìpínlẹ̀ Oǹdó. Ìwádìí fihàn wí pé àwọn ìlú bí Ejurín, Ìlíṣà, Ìṣàyà, Ìgbèṣí, Àhàn, Ìlúdọ̀fin, Orújú, Ìwòrò, Ìráfún ni ó parapọ̀ di Òmùò òkè, Ọláitan àti Ọládiípò (2002:3) Iṣẹ́ òòjọ́ wọn ni iṣẹ́ àgbẹ̀ àti òwò ṣíṣe. Ìdí ti wọn fi ń ṣe iṣẹ́ òwò ni wí pé, Òmùò òkè ni wọn ti máa ń kò ẹrù lọ sí òkè ọya. Ẹ̀ka èdè Òmùò-òkè yàtọ̀ sí Òmùò kọta Òmùò Ọbádóore. Òmùò Èkìtì jẹ́ àpapọ̀ ìlú mẹ́ta.
{{Infobox settlement
|name = Òmùò-òkè
|settlement_type =
|image_skyline =
|imagesize =
|image_alt =
|image_caption =
|image_flag =
|flag_size =
|flag_alt =
|image_seal =
|seal_size =
|seal_alt =
|image_shield =
|shield_size =
|shield_alt =
|image_blank_emblem =
|blank_emblem_type =
|blank_emblem_size =
|blank_emblem_alt =
|nickname =
|motto =
|image_map =
|mapsize =
|map_alt =
|map_caption =
|image_map1 =
|mapsize1 =
|map_alt1 =
|map_caption1 =
|image_dot_map =
|dot_mapsize =
|dot_map_base_alt =
|dot_map_alt =
|dot_map_caption =
|dot_x = |dot_y =
|pushpin_map = Nigeria
|pushpin_label_position = bottom
|pushpin_map_alt =
|pushpin_mapsize =
|pushpin_map_caption = Location in Naijiria
|latd =7 |latm =46 |lats =0 |latNS = N
|longd = 5|longm =45 |longs = 0|longEW = E
|coor_pinpoint =
|coordinates_type =
|coordinates_display =
|coordinates_footnotes =
|subdivision_type = Country
|subdivision_name = [[Image:Flag of Nigeria.svg|25px]] [[Nigeria]]
|subdivision_type1 = [[Awon Ipinle Naijiria|Ipinle]]
|subdivision_name1 = [[Ipinle Ekiti]]
|subdivision_type2 =
|subdivision_name2 =
|established_title =
|established_date =
|founder =
|named_for =
|seat_type =
|seat =
|government_footnotes =
|government_type =
|leader_party =
|leader_title =
|leader_name =
|leader_title1 =
|leader_name1 =
|total_type =
|unit_pref =
|area_magnitude =
|area_footnotes =
|area_total_km2 =
|area_total_sq_mi =
|area_total_dunam =
|area_land_km2 =
|area_land_sq_mi =
|area_water_km2 =
|area_water_sq_mi =
|area_water_percent =
|elevation_footnotes =
|elevation_m =
|elevation_ft =
|population_footnotes =
|population_total =
|population_as_of =
|population_density_km2 =
|population_density_sq_mi=
|population_est =
|pop_est_as_of =
|population_note =
|timezone1 =
|utc_offset1 =
|timezone1_DST =
|utc_offset1_DST =
|postal_code_type =
|postal_code =
|area_code_type =
|area_code =
|website =
|footnotes =
}}
[[Omuo-Oke-Ekiti]]
 
[[I.A. Owolabi]]
 
I.A. Owólabí (2005), ‘Òmuò-Òkè-Èkìtì’, láti inú ‘fọnọ́lọ́jì Ẹ̀ka-èdè Òmìò-Òkè-Èkìtì’,. Àpilẹ̀kọ fún Oyè Ẹ́meè, ojú-ìwé 1-3.
 
Ìfáárà
Àwọn ohun tí a gbé yẹ̀wò nínú orí kìn-ín-ní yìí ni àlàyé lórí ìtàn ìṣẹ̀dálẹ̀ ìlú Òmùò-òkè Èkìtì. A mẹ́nuba oríṣìíríṣìí ọ̀nà tí a gbà ṣe ìwádìí àti iṣẹ́ tí àwọn onímọ̀ ti ṣe lórí ẹ̀ka èdè, ni àgbéyẹ̀wò lítírésọ̀. Ohun ti a fi kásẹ̀ àlàyé wa ní orí yìí nib í iṣẹ́ àpilẹ̀kọ yìí ṣe fẹ̀ tó àti tíọ́rì ti a ṣe àmúlò rẹ̀.
 
==ÌLÚ ÒMÙÒ-ÒKÈ-ÈKÌTÌ==
Ìlà oòrùn Èkìtì ni Òmùò òkè wà. Ìjọba ìbílẹ̀ ìlà Oòrùn ni ìpínlẹ̀ Èkìtì ni Òmùò-òkè tẹ̀dó sí. Òmùò-òkè tó kìlómítà méjìlélọ́gọ́ọ̀rin sí Adó-Èkìtì tí ó jé olú-ìlú ìpínlẹ̀ Èkìtì. Òmùò-òkè ni ìpínlẹ̀ Èkìtì parí sí kí a tó máa- lọ sí ìpìnlẹ̀ Kogi. Ìdí nìyí tí ó fi bá àwọn ìlú bí i, Yàgbà, Ìjùmú, Ìyàmoyè pààlà. Bákan náà ni ó tún bá Erítí Àkókó pààlà ní ìpínlẹ̀ Oǹdó. Ìwádìí fihàn wí pé àwọn ìlú bí Ejurín, Ìlíṣà, Ìṣàyà, Ìgbèṣí, Àhàn, Ìlúdọ̀fin, Orújú, Ìwòrò, Ìráfún ni ó parapọ̀ di Òmùò òkè, Ọláitan àti Ọládiípò (2002:3) Iṣẹ́ òòjọ́ wọn ni iṣẹ́ àgbẹ̀ àti òwò ṣíṣe. Ìdí ti wọn fi ń ṣe iṣẹ́ òwò ni wí pé, Òmùò òkè ni wọn ti máa ń kò ẹrù lọ sí òkè ọya. Ẹ̀ka èdè Òmùò-òkè yàtọ̀ sí Òmùò kọta Òmùò Ọbádóore. Òmùò Èkìtì jẹ́ àpapọ̀ ìlú mẹ́ta.
 
# Òmùò-òkè Èkìtì
Line 119 ⟶ 7:
Èdè Òmùò-òkè farapẹ́ èdè Kàbbà, Ìgbàgún àti Yàgbàgún ni ìpinlẹ̀ Kogi. O ṣe é ṣe kí èyí rí bẹ́ẹ̀ nítorí Òmùò-òkè ló bá ìpínlẹ̀ Kogí pààlà. Bákan náà ni àwọn ènìyàn Òmùò-òkè máa ń sọ olórí ẹ̀ka èdè Yorùbá àti èdè Gẹ̀ẹ́sì ni pàápàá àwọn tó mọ̀ọ̀kọ̀-mọ̀ọ́kà.
 
==Ìtàn ìṣẹ̀dálẹ̀ rẹ̀==
==ÌTÀN ÌSẸ̀DÁLẸ̀ ÒMÙÒ ÒKÈ==
Ìtàn àgbọ́sọ ni ó rọ̀ mọ́ ìtàn ìsẹ̀dálẹ̀ ìlú Òmùò-òkè gẹ́gẹ́ bí ó ṣe rí ni àwọn ilẹ̀ Yorùbá káàkiri. Ilé-Ifẹ̀ ni orírun gbogbo ilẹ̀ Yorùbá bẹ́ẹ̀ ló ṣe rí ní Òmùò-òkè.