Sunday Ìgbòho: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Content deleted Content added
New Page
Àwọn àlẹ̀mọ́: Àtúnṣe ojú fóónù Àtúnṣe ojú fóónù Advanced mobile edit
(Kò ní yàtọ̀)

Àtúnyẹ̀wò ní 14:20, 23 Oṣù Kínní 2021

Chief Sunday Ìgbòho tí orúkọ àbísọ rẹ̀ gan-an ń jẹ́ Sunday Adéníyì Adéyẹmọ (tí wọ́n bí lọ́jọ́ kẹwàá oṣù kẹwàá ọdún 1972 [1]) jẹ́ gbajúmọ̀ ajìjàǹgbara, olóṣèlú àti ajàfẹ́tọ̀ọ́ ọmọ ènìyàn ọmọ bíbí Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ lórílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Ó jẹ́ ajìjàǹgbara fún ìdásílẹ̀ orílẹ̀-èdè Oòduà àti ìṣọ̀kan àwọn ọmọ Yorùbá káàkiri Nàìjíríà.[2] Òun ni alága àti olùdásílẹ̀ ilé-iṣẹ́ Adeson International Business Concept Ltd, bẹ́ẹ̀ náà Wọ́n fi òye Akọni Oòduà ilẹ̀ Yorùbá dáa lọ́lá.[3] Sunday di gbajúmọ̀ ìlúmọ̀ọ́ká lórí ìkànnì abánidọ́rẹ̀ẹ́ lósù kìíní ọdún 2021 nígbà tí ó àwọn darandaran Fúlàní ní gbèǹdeke ọjọ́ méje láti kúrò nílẹ̀ Ìbàràpá nítorí ìpakúpa tí wọ́n fura pé àwọn Fúlàní wọ̀nyí ló pa Ọ̀mọ̀wé Abọ́rọ̀dé.[4][5]

Chief
Sunday Igboho
Ọjọ́ìbíSunday Adeniyi Adeyemo
(1972-10-10)10 Oṣù Kẹ̀wá 1972
Igboho town, Oke ogun, Oyo state
Iṣẹ́Human rights activist, politician

Àwọn ìtọ́kasí

  1. "Seven things to know about Sunday Igboho". Latest Nigeria News, Nigerian Newspapers, Politics (in Èdè Latini). 2021-01-23. Retrieved 2021-01-23. 
  2. Nenge, Katrine (2018-10-16). "Handsome and successful: The story of Sunday Igboho’s". Legit.ng - Nigeria news. (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2021-01-21. 
  3. Alao, Moses. "2019: I Inherited Powers To Command Guns From My Father —Sunday Igboho". tribuneonlineng.com. Retrieved 2021-01-21.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  4. "INSECURITY: Why Fulani herders must leave Oyo - Igboho". Vanguard News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2021-01-19. Retrieved 2021-01-21. 
  5. "Nothing must happen to Igboho, Ibarapa Youths warn FG, Oyo govt". Vanguard News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2021-01-20. Retrieved 2021-01-21.