Doyin Okupe: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Content deleted Content added
Ìlà 14:
Gónìnà àná tẹ́lẹ̀ rí ní [[Ìpínlẹ̀ Ògùn]] [[Segun Osoba|Olóyè Olúṣẹ́gun Ọ̀ṣọbà]] fìdí rẹ̀ múlẹ̀ nínú ìfọ̀rọ̀wáni-lẹ́nu wò kan tí ó wáyé pẹ̀lú Ilé-iṣẹ́ ìwé-ìròyìn The Nation (Nigeria), nínú oṣù Keje ọdún 2019, wípé <nowiki>''</nowiki> Dókítà Doyin Òkúpè àti akẹgbẹ́ rẹ̀ Dókítà Ṣèyí Roberts ni wọ́n dóòlà èmí aṣọ́gbà mi kan lọ́wọ́ ikú ọta [[Ìbọn]] tí ó bàá ní orí ní ọjọ́ Kẹtalélógún oṣù Keje ọdún 1994<nowiki>''</nowiki>.<ref name="Nation">{{Cite news|url=https://thenationonlineng.net/how-i-escaped-assassination-four-times-by-osoba/|title=How I escaped assassination four times, by Osoba|date=2 July 2019|access-date=25 May 2020}}</ref>
 
=== Ṣíṣe Ìṣèlú rẹ̀ ===
Ní àsìkò Ìṣèjọba alágbára ẹlẹ́kejì ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, Òkúpè jẹ́ ọmọ ilé ìgbìmọ̀ aṣojú-àárín àgbà ní abẹ́ ẹgbẹ́ òṣèlú [[National Party of Nigeria|National Party of]] Nigeria (NPN) nínú [[Ìdìbò ọdún 1983]].
 
Ìlà 27:
200ó ìdíje dupò gómìnà ní abẹ́ ẹgbẹ́ òṣèlú PDP nínú ìdìbò abẹ́lé ẹgbẹ́ wọn, amọ́ oyè náà já mọ́ th [[Gbenga Dáníẹ́l|Gbenga Dan lọwọ́iel]].<ref name="ThisDay2">{{Cite news|url=https://allafrica.com/stories/200207090434.html|title=Okupe's Group Leads in Ogun PDP Primaries|author=Chris Anucha|date=9 July 2002|access-date=25 May 2020}}</ref> Ààrẹ [[Goodluck Jonathan]] yan Òkúpè gẹ́gẹ́ bí Olùràn lọ́wọ́ pàtàkì lórí ọ̀rọ̀ iṣẹ́ òde ní ọdún 2012.<ref name="ThisDay">{{Cite news|title=Jonathan Appoints Okupe Aide|url=http://www.thisdaylive.com/articles/jonathan-appoints-okupe-aide/120938/|date=27 July 2012|access-date=26 April 2014|work=[[This Day|ThisDay Live]]}}</ref><ref name="Punch">{{Cite news|title=Okupe appointed Jonathan's adviser|url=http://www.punchng.com/news/okupe-appointed-jonathans-adviser/|date=27 July 2012|access-date=26 April 2014|work=[[The Punch|Punch Newspaper]]}}</ref><ref name="DailyIndependent">{{Cite news|title=Jonathan appoints Okupe SSA Public Affairs|url=http://dailyindependentnig.com/2012/07/jonathan-appoints-okupe-ssa-public-affairs/|access-date=26 April 2014}}</ref>
 
Okupe jẹ olùpolongo àgbà fún ẹgbẹ́ òṣèlú PDP pàá pàá jọ sí gbogbo àwọn olùdíje sí ipò Ààrẹ ní abè ẹgbẹ́ òṣèlú rẹ̀ láti orí ni [[Olúṣẹ́gun Ọbásanjọ́]], [[Goodluck Jonathan]] , [[Bukola Saraki]] àti [[Atiku Abubakar]] . <ref name="Guardian">{{Cite news|url=https://guardian.ng/news/saraki-appoints-doyin-okupe-head-of-campaign-media-council/|title=Saraki appoints Doyin Okupe head of Campaign media council|author=Abisola Olasupo|date=11 September 2018|access-date=25 May 2020}}</ref> <ref name="TheCable2">{{Cite news|url=https://www.thecable.ng/just-in-efcc-arraigns-okupe-for-n702m-fraud|title=EFCC arraigns Okupe for 'N702m fraud'|author=Chinedu Asadu|publisher=[[TheCable]]|date=14 January 2019|access-date=27 May 2020}}</ref> Ó kéde èrò ọkàn rẹ̀ láti kúrò nínú ẹgbẹ́ PDP kí ó sì dara pọ̀ mọ́ ẹgbẹ́ ìṣèlú Accord ní ọdún 2017. Ẹgbẹ́ òṣèlú Accord le kúrò nínú ẹgbẹ́ òṣèlú wọn ní ọdún 2018, látàrí wípé ó gbà láti ṣe alukoro àti olùpolongo ìbò fún olùdíje sípò Ààrẹ lábẹ́ ẹgbẹ́ẹ́ òṣèlú PDP, ìyẹn Bùkọ́lá Sàrakí ní ọdún 2018. Ó padà sínú ẹgbẹ́ Òṣèlú PDP tí ó sì jẹ́ agbẹnusọ àgbà fún olùdíje sípò ààr3 àyà Atiku Abubakar ní ọdún 2019. <ref name="TheCable3">{{Cite news|url=https://web.thecable.ng/okupe-joins-accord-party-says-not-desperate-anything|title=Okupe joins Accord party, says he is not desperate to be anything|author=Fredrick Nwabufo|publisher=[[TheCable]]|date=18 July 2017|access-date=25 May 2020}}</ref> <ref name="DailyPost">{{Cite news|url=https://dailypost.ng/2018/09/13/accord-party-expels-doyin-okupe-gives-reason/|title=Accord party expels Doyin Okupe, gives reason|author=Chijioke Jannah|publisher=[[Daily Post (Nigeria)]]|date=13 September 2018|access-date=26 May 2020}}</ref> <ref name="DailyPost2">{{Cite news|url=https://dailypost.ng/2018/11/11/2019-presidency-returned-pdp-doyin-okupe/|title=2019 Presidency: Why I returned to PDP – Doyin Okupe|author=Fikayo Olowolagba|publisher=[[Daily Post (Nigeria)]]|date=11 November 2018|access-date=26 May 2020}}</ref>
 
== Ìgbésí ayé rẹ̀ ==