Kíndìnrín: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Content deleted Content added
No edit summary
kNo edit summary
Àwọn àlẹ̀mọ́: VisualEditor Àtúnṣe ojú fóónù Àtúnṣe ojú fóónù
Ìlà 15:
}}
 
'''kíndìnrín''' jẹ́ àwọn ẹ̀yà ara inú méjì tí Ìrísí wọn dà bí [[ẹ̀wà]], tí a lè ṣalábàápàdé rẹ̀ ní araárá gbogbogbógbó ẹranko elégungunélégúngún. Àwọn kíndìrín yí wà ní apá ọ̀tún àti apá òsí ní ìsàlẹ̀ àyà. Àwọn kíndìnrín wọ̀nyí ma ń gba [[ẹ̀jẹ̀]] sára láti ara [[iṣan]] tí ó so pọ̀ mọ́ ọkàn tí wọ́n ń pè ní [[renal artery|renal arteriee]]. Kíndìnrín kọ̀ọ̀kan ni ó tún so mọ́ [[iṣan]] mìíràn tí wọ́n ń pè ní (ureter), iṣan yí ni ó ń ran àwọn kíndìnrín yí lọ́wọ́ láti máa gbé [[ìtọ̀]] láti inú kíndìnrín lọ sí inú ilé tàbí àpò ìtọ̀ tí wọ́n ń pè ní (bladder).
==Àtúpalẹ̀ iṣẹ́ Kíndìrín==
Nínú kíndìnrín kọ̀ọ̀kan ni a ti rí àwọn iṣàn wẹ́wẹ̀wẹ́ í orúkọ wọn ń jẹ́ (nephron) tí ó tó Mííọ́nù kan níye, tí wọn kò tẹ́ẹ́rẹ́ ju irun orí lọ tí [[ojú]] lásán kò lè rí, àyàfi pẹ̀lú ìrànlọ́wọ́ ìwògbè (microscope), tí àwọn iṣan wẹ́wẹ̀wẹ́ wọ̀nyí náà tún gbọ́mọ pọ̀n. Nínú àwọn iṣan wẹ́wẹ́ yìí ni ìṣàyípadà ní [[omi]] àti [[ẹ̀jẹ̀]] tí kò wúlò fún ara mọ́ ti ma ń yí padà sí ìtọ̀ tí yóò sì bá ojú ara ọkùnrin àti obìnrin jáde láti ilé ìtọ̀. Bákan náà ni kíndìnrín tún ń kópa pàtàkì nínú ṣíṣètò àti dídarí omi,ẹ̀jẹ̀, ásíídì, àti yíyọ àwọn ohun tí kò da kúrò lára. Kíndìnrín ni a lè pè ní asẹ́ tí ó ń jọ gbogbo ohun bíi omi, ẹ̀jẹ̀, àti ásíídì àti àwọn nkan mìíràn tó bá gba ọ̀dọ̀ rẹ̀ kọjá .<ref name="robbins">{{cite book |author1=Cotran, RS S. |author2=Kumar, Vinay |author3=Fausto, Nelson |author4=Robbins, Stanley L. |author5=Abbas, Abul K. |title=Robbins and Cotran pathologic basis of disease |publisher=Elsevier Saunders |location=St. Louis, MO |year=2005 |pages= |isbn=978-0-7216-0187-8 |oclc= |doi= |accessdate=}}</ref>