Ilé kòkó: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Content deleted Content added
Created by translating the page "Cocoa House"
(Kò ní yàtọ̀)

Àtúnyẹ̀wò ní 15:18, 6 Oṣù Kẹta 2021

Ilé Cocoa, tí wọ́n kọ́ ní ọdún 1965 tí gíga tó ẹsẹ bàtà mítà márùnlé-lógọ́rún, [1] jẹ́ ilé tí ó ga jùlọ ní iwọ̀ oòru Afíríkà. Dùgbẹ̀ ní iìlú Ibadan ni Ìpínle Ọ̀yọ́, orílẹ̀ èdè Nàìjíríà ni wọ́n kọ sí. Èrè owò ọ̀gbìn (bíi Kòkó, Rọ́bà, igi) ti ìpínle ìwọ̀-oòrún ti orílẹ̀ èdè Nàìjíríà ni wọ́n sì fí kọ́ ọ́.

Ile koko

Orúkọ àkọ́kọ́ tí wọ̣́n fún ilé náà ni 'Ilé àwọn àgbẹ̀', tí ó túmọ̀ l'éde Gẹ̀ẹ́sì sí 'the house of farmers. Wọ́n padà yí orúkọ yìí sí 'ilé kòkó' nítorí wípé èrè owò ọ̀gbìn pàápàá jùlọ́ owó tí wọ́n rí látàri òwò ti ìpínle ìwọ̀-oòrún ti orílẹ̀ èdè Nàìjíríà ni wọ́n sì fí kọ́ ọ́

  1. Anthony Nkem Ede. Challenges Affecting the Development and Optimal Use of Tall Buildings in Nigeria. The International Journal of Engineering and Science. https://archive.org/stream/Httptheijes.com_201405/B03402012020_djvu.txt. Retrieved April 4, 2014.