Aliyu Magatakarda Wamakko: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Content deleted Content added
kNo edit summary
 
Ìlà 17:
A bí '''Aliyu Magatakarda Wamakko''' ní ọjọ́ kínní, Oṣù Kẹ́ta, Ọdún 1953. Ní Ọdún 2007, nínú Oṣù kẹẹ̀rin wọ́n dìbò yàn-án sí ipò Gómìnà [[Ìpínlẹ̀ Ṣókótó]], ní orílẹ̀-èdè [[Nàìjíríà]], lẹ́ni tó ń ṣe aṣojú ọmọ ẹgbẹ́ òṣèlú [[People's Democratic Party]], (PDP). Ẹgbẹ́ yìí ni a mọ̀ sí ẹgbẹ́ Òní "umbrella".
==Ètò-ẹ̀kọ́ ati iṣẹ́ rẹ̀==
Ó lọ sí ilé ẹ̀kọ́ àwọn Olùkọ́ni tí a mọ̀ sí Teachers' College, nilùú Ṣókótó, láàrín ọdún 1968 sí ọdún 1972, léyìí tó lo ọdún márùn ún gbáko. Lẹ́yìn tó parí ẹ̀kọ́ rẹ̀, ó ṣiṣẹ́ olùkọ́ni láàrín ọdún 1973 sí 1977, kó tó wá lọ sí Ilé ẹ̀kọ́ gíga Fásitì, Univercity of Pittsburgh ní orílẹ̀-èdè [[Amẹ́ríkà]]. Ó parí ẹ̀kọ́ Fásitì, ó sì gboyè B.Sc. ní oṣù kẹjọ, ọdún 1980. Ó padà sí Ilẹ̀ Nàìjíríà, o ṣiṣẹ́ akẹ́ẹ̀kọ́ níle ẹ̀kọ́ olùkọ́ni, ìyẹn Ṣókótó Teachers'

College.
Wamakko, ṣiṣẹ́ ní ilé-iṣẹ́ Ìjọba Ìbílẹ̀ Zumi mi gẹ́gẹ́ bíi igbákejì akọ̀wé. Wọ́n gbéga lẹ́nu iṣẹ́ rẹ̀ lọ sípò adelé akọ̀̀̀̀̀̀̀̀̀̀̀̀̀̀̀wé. Ó tún ṣiṣé ní ìjọba ìbílẹ̀ Kaura Namoda. Wọn yan sípò Alága ìjọba Ìbílẹ̀ Ṣókótó, láti ọdún 1986 sí ọdún 1987.
Wamakko di ọ̀gá pátápátá ilé iṣẹ́ ibi Igbafẹ́ fáwọn arìnrìn-àjò àti ilé ìtura, ní Ṣókótó. Ní ọdún 1992, oṣù kẹ́ta, Wamakko ní ìgbéga sí ipò Olùdari àgbà fún àwọn àkànṣe iṣẹ́, ní ọ́fíìsì Gọ́mìnà, ní Ìpinlẹ̀ Ṣókótó.
==Ètò ìṣèlú rẹ̀==