Omi: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Content deleted Content added
Mo fi àwọn kúlẹ̀kúlẹ̀ àti àwòrán mẹ́ta kún un
kNo edit summary
Ìlà 1:
[[Fáìlì:Water droplet blue bg05.jpg|right|thumb|229x229px|Omi]]
 
'''Omi''' jẹ́ kókoohun elégbó tí ó ṣe pàtàkì fún gbogbo ohun ẹlẹ́mìí. Omi ò lóòórùn, kò ní àwọ̀ àti bẹ́ẹ̀ ni kò ní adùn, ó jẹ́ èròjà tó pọ̀ nínú afẹ́fẹ́, ilẹ̀ àti òkun. Omi tún wà nínú apáara gbogbo ohun olómiẹlẹ́mìí ti araó gbogboma ohunń ẹlẹ́mìíyòrò. (gẹ́gẹ́<ref bíiname="USGS.gov">{{cite [[ohunweb alèyòrò]])| title=The Water in You: Water and the Human Body | website=USGS.gov | url=https://www.usgs.gov/special-topic/water-science-school/science/water-you-water-and-human-body?qt-science_center_objects=0#qt-science_center_objects | access-date=2021-04-10}}</ref>
 
"Omi" ni orúkọ àdàpè tí àwọn Gẹ̀ẹ́sì ń pèé ní H<sub>2</sub>O0 ní ipò ṣíṣàn, àti ní ìwọ̀n ooru àyíká. Ní ipò yìí omi lè di ohun tí ń rọ̀ bíi òjò, tàbí ohun tí afẹ́fẹ́ ń gbé bí kùrukùru. A lè rí ìkùukùu nígbà tí omi àti omi dídì bá ṣù pọ̀ lójú sánmà. Nígbà tí omi náà bá ṣèpínyà, omi dídì oníkírísítálì lè já bọ́ gẹ́gẹ́ bí yìnyín. À ń pè omi onípò gáàsì ní oruku omi. Omi máa ń yí ipò rẹ̀ ní ìpele kọ̀ọ̀kan ti ''ìyípoyípo omi''. Bí ìyípopyípo omi ṣe ń ṣẹlẹ̀ rèé: Kùrukùru omi yóò gòkè lọ sójú sánmà, yóò wá di òjò. Òjò náà yóò wá rọ̀, yóò sì wọnú àwọn adágún, àwọn ọ̀sà, àti àwọn odò, yóò sì “rin ilẹ̀ ayé gbingbin.” Lẹ́yìn èyí, omi sábà máa ń wọnú òkun lẹ́ẹ̀kan sí i.
 
== Ìjẹ́pàtàkì rẹ̀ fún ọ̀làjú ènìyàn ==
Jẹ́ kíkójáde láti "https://yo.wikipedia.org/wiki/Omi"