Omi: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Content deleted Content added
kNo edit summary
kNo edit summary
Ìlà 1:
[[Fáìlì:Water droplet blue bg05.jpg|right|thumb|229x229px|Omi]]
 
'''Omi''' jẹ́ ohun tí ó ṣe pàtàkì fún gbogbo ohun ẹlẹ́mìí. Omi ò lóòórùn, kò ní àwọ̀ àti bẹ́ẹ̀ ni kò ní adùn, ó jẹ́ èròjà tó pọ̀ nínú afẹ́fẹ́, ilẹ̀ àti òkun. Omi tún wà nínú ara gbogbo ohun ẹlẹ́mìí tí ó ma ń yòrò. <ref name="USGSwww.govdictionary.com 2020">{{cite web | title=TheDefinition Waterof in You: Water and the Human Bodywater | website=USGSwww.dictionary.govcom | date=2020-09-17 | url=https://www.usgsdictionary.govcom/special-topicbrowse/water-science-school/science/water-you-water-and-human-body?qt-science_center_objects=0#qt-science_center_objects | access-date=2021-04-10}}</ref>
 
"Omi" ni orúkọ àdàpè tí àwọn Gẹ̀ẹ́sì ń pèé ní H<sub>2</sub>0 ní ipò ṣíṣàn. Ní ipò yìí omi lè di ohun tí ń rọ̀ bíi òjò, tàbí ohun tí afẹ́fẹ́ ń gbé bí kùrukùru. A lè rí ìkùukùu nígbà tí omi àti omi dídì bá ṣù pọ̀ lójú sánmà. Nígbà tí omi náà bá ṣèpínyà, omi dídì oníkírísítálì lè já bọ́ gẹ́gẹ́ bí yìnyín. À ń pè omi onípò gáàsì ní oruku omi. Omi máa ń yí ipò rẹ̀ ní ìpele kọ̀ọ̀kan ti ''ìyípoyípo omi''. Bí ìyípopyípo omi ṣe ń ṣẹlẹ̀ rèé: Kùrukùru omi yóò gòkè lọ sójú sánmà, yóò wá di òjò. Òjò náà yóò wá rọ̀, yóò sì wọnú àwọn adágún, àwọn ọ̀sà, àti àwọn odò, yóò sì “rin ilẹ̀ ayé gbingbin.” Lẹ́yìn èyí, omi sábà máa ń wọnú òkun lẹ́ẹ̀kan sí i.
 
== Ìjẹ́pàtàkìPàtàkì rẹ̀omi fún ọ̀làjú ènìyàn ==
[[Fáìlì:Lagos Lagoon, Nigeria.jpg|thumb|229x229px|[[Lagos Lagoon|Ọ̀sà Èkó]]]]
Ní ìgbà ìgbàanì, etí odò tàbí ìladò ni ọ̀lájú máa ń gbòòrò: [[Mesopotámíà]] wà láàárín odò méjì tó ṣe pàtàkì — [[Odò Tígírísì]] àti [[Odò Yúfírétì]]; [[Nílò|Odò Náílì]] ṣe kókó fún Íjíbítì ìgbàanì. Ọ̀làjú àfonífojì Indus ìjímìjí (c. 3300 BCE to 1300 BCE) dàgbàsókè lẹ́bàá [[Odò Indus]] àti àwọn odò míì tí ń ṣàn láti [[Himalaya|òkè Himalaya]]. Wọ́n kọ́ Ìlú [[Rómù Olómìnira|Róòmù ìgbàanì]] ní bèrè Odò Táíbà tó wà lórílẹ̀-èdè Ítálì. Àwọn ìgboro ìlú ńlá ìgbàlóde bíi [[Èkó]], [[Lọndọnu|Lọ́ńdọ́nù]], [[Tokyo]], [[Parisi]], Montreal, Rotterdam, Shanghai, Buenos Aires, New York àti [[Ṣìkágò]] ti gbòòrò lápá kan nítorí wọ́n láǹfààní sí omi. Àwọn erékùṣù tó ní èbúté aláìléwu, gẹ́gẹ́ bí [[Singapore]], ti dọlọ́rọ̀ nítorí ìdí ọ̀hún bákan náà. Ní ẹkùn ilẹ̀ aláìtó omi gẹ́gẹ́ bíi [[Àríwá Áfríkà|apá àríwá Áfíríkà]] àti Ilẹ̀ Lárúbáwá, àǹfààní omi tó ṣeé mu ti ń ṣe kókó fún ìdàgbàsókè ènìyàn.
<ref name="USGS.gov">{{cite web | title=The Water in You: Water and the Human Body | website=USGS.gov | url=https://www.usgs.gov/special-topic/water-science-school/science/water-you-water-and-human-body?qt-science_center_objects=0#qt-science_center_objects | access-date=2021-04-10}}</ref>
 
 
=== Ìlera àti Ìbàyíkájẹ́ ===
Line 17 ⟶ 19:
== Àṣà ==
 
=== Ìgbàgbọ́ àti Ẹ̀sìn nípa omi ===
[[Fáìlì:River-SideShrineAndSacredGroveOfOsun.jpg|thumb|228x228px|Ojúbọ Ọ̀ṣun létí Odò Ọ̀ṣun ]]
Nínú ẹ̀sìn púpọ̀, wọ́n ka omi sí ohun mímọ́. Ààtò-ìsìn wíwẹ̀ wà nínú àwọn ẹ̀sìn mélòó kan, bí àpẹẹrẹ: [[Ìmàle|Ẹ̀sìn Ìmàle]], [[Ẹ̀sìn Krístì|Ẹ̀sìn Kírísítì]], [[Ìsìn Júù]], [[Ìṣẹ̀ṣe]], Ẹ̀sìn àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ. Ní ẹ̀sìn Kírísítì, wọ́n máa ń ṣe ''ìrìbọmi'' gẹ́gẹ́ bíi ''ìyàsímímọ́''. Ẹ̀sìn Ìmàle ń ṣe ''ghusl'' kí wọ́n tó gbàdúrà.
Line 24 ⟶ 26:
 
{{ekunrere}}
==Àwọn ìtọ́ka sí==
 
{{commons|Category:Water}}
[[Ẹ̀ka:Omi]]
Jẹ́ kíkójáde láti "https://yo.wikipedia.org/wiki/Omi"