Giorgos Seferis: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

File
(DEFAULTSORT)
(File)
 
| awards = {{Awd|[[Nobel Prize in Literature]]|1963}}
}}
[[File:George Seferis.JPG|200px|thumb|Seferis (1921)]]
 
'''Giorgos''' tabi '''George Seferis''' (Γιώργος Σεφέρης) ni orúkọ [[pen name|ìnagijẹ]] '''Geōrgios Seferiádēs''' (Γεώργιος Σεφεριάδης, {{OldStyleDate|13 March|1900|29 February}} - September 20, 1971). Òhun ni olùkọ̀wé ọmọ orílẹ̀ èdè [[Greece]] tó ṣe pàtàkìjùlọ ní bíi ogún ọrundún sẹ́yìn, tí ó gba ẹbun [[Nobel Prize|Nobel]]. Ó tún ṣisẹ́ bíi aṣojú orílẹ̀ èdè rẹ̀ ní Greek Foreign Service, kí wọ̣́n tó yànhán gẹ́gẹ́ bí [[Ambassador|asojú]] sí [[United Kingdom|UK]], ibi tó wà lati ọdún 1957 sí 1962.