Ladi Kwali: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Content deleted Content added
kNo edit summary
kNo edit summary
Ìlà 3:
| death_date = {{death date and age|1984|8|12|1925|mf=y}}
| birth_place = [[Kwali]], Nigeria
| occupation = [[Pottery|Potter amọ̀kòmkò]]
| birth_name = Ladi Kwali
}}
'''Ladi Kwali''', [[Order of the Niger|OON]], [[Order of the British Empire|MBE]] (c.1925– August 12, 1984)<ref>{{Cite web|url=http://www.thistrend.com.ng/2017/03/15-facts-about-ladi-kwali-pottery-woman.html|archive-url=https://web.archive.org/web/20170317101452/http://www.thistrend.com.ng/2017/03/15-facts-about-ladi-kwali-pottery-woman.html|url-status=dead|archive-date=2017-03-17|title=15 Facts about Ladi Kwali: The Pottery Woman on N20 Note - ThisTrend Blog|date=2017-03-17|access-date=2018-08-06}}</ref> wasjẹ́ aamọ̀kòmkò Nigerianọmọ orílẹ̀-èdè [[pottery|potterNàìjíríà]].
 
Ladi Kwali ni wọ́n bí ní [[abúlé]] kan tí ó ń jẹ́ Kwali ni agbègbè [[Gbwari]] ní apá òkè ọyà ní orílẹ̀-èdè [[Nàìjíríà]] ìlú tí [[ìkòkò]] ṣíṣe ti jẹ́ iṣẹ́ òójọ́ fún àwọn [[obìrin]] wọn.<ref name=":3">{{Cite book|title=Women and Ceramics: Gendered Vessels|last=Vincentelli|first=Moira|publisher=Manchester University Press|year=2000|isbn=978-0719038402|location=Manchester, UK|pages=[https://archive.org/details/womenceramics00moir/page/58 58–76]|url=https://archive.org/details/womenceramics00moir/page/58}}</ref> Ladi kọ́ bí wọ́n ṣe ń Mọ ìkòkò láti ìgbà tí ó ti wà ní ọmọdé lọ́dọ̀ ìkan lara àwọn mọ̀lẹ́bí bàbá rẹ̀. Ìlànà [[Coiling (pottery)|coiling]] ni wọ́n ń ló láti fi Mọ ìkòkò nígbà náà. Ladi ni ó ti lo ìṣeẹ́ ọwọ́ rẹ̀ yí láti fi ṣe àwọn ohun èlò ilé bíi: ìkòkò orù, ìkòkò àmù, ìkòkò [[ọbẹ̀]] láti inú amọ̀ tí wọ́n pò pọ̀. Àwọn iṣẹ́ ọwọ́ rẹ̀ yí ni ó ṣe ọ̀ṣọ́ oríṣiríṣi sí pẹ̀lú àwọn àwòrán onírúurú bíi [[akekèé]], [[alàgbà]], [[ọ̀ọ̀nì]], [[ejò]], [[àyà]] [[ẹja]] àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ.<ref name=":1">{{Cite journal|last=Cardew|first=Michael|date=April 1972|title=Ladi Kwali: The Potter from England Writes on the Potter from Africa|journal=Craft Horizons|issue=32|pages=34–37}}</ref> Gbogbo àwọn ẹ̀ṣọ́ tí a mẹ́nu bà wípé ó ma ń ṣe sí ara àwọn iṣẹ́ ọwọ́ rẹ̀ yí ni ó ma ń fi dárà lẹ́yìn tí ó bá ti sun amọ̀ náà nínú iná tí ó sì ti di ìkòkò ní ìlànà bí wọ́n ṣe ń ṣe ìkòkò ní Kwali. Ọnà ìṣe ìkòkò Ladi ni ó mu di gbajú-gbajà àmọ̀-kòkò nílé àti lókè òmun. <ref>{{Cite journal|last=Thompson|first=Barbara|date=6 February 2007|title=Namsifueli Nyeki: A Tanzanian Potter Extraordinaire|journal=African Arts|volume=40|issue=1|pages=54–63|doi=10.1162/afar.2007.40.1.54|s2cid=57571884|issn=0001-9933}}</ref> Púpọ̀ nínú àwọn [[ìṣeẹ́ ọnà]] rẹ̀ ni ìkan lára àwọn Ọba àwọn [[Hausa]] ní ìlú [[Àbújá]] ìyẹn Alhaji [[Sulaimanu Barau|Suleiman Barau]],<ref name=":0">{{Cite web|url = http://www.abujafacts.ng/history-of-ladi-kwali-the-famous-nigerian-potter/|title = History of Ladi Kwali, the Famous Nigerian Potter|date = 8 February 2015|access-date = 18 January 2016|website = Abuja Facts|archive-url = https://web.archive.org/web/20160107104939/http://www.abujafacts.ng/history-of-ladi-kwali-the-famous-nigerian-potter/|archive-date = 7 January 2016|url-status = dead}}</ref> ń sábà ma ń fowó rà nígbà ayé rẹ̀.
Jẹ́ kíkójáde láti "https://yo.wikipedia.org/wiki/Ladi_Kwali"