Ejò: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Content deleted Content added
kNo edit summary
kNo edit summary
Ìlà 40:
Àwọn ejò tí wọ́n wà láàyè ni wọ́n wà ní oríṣiríṣi ibi ati ilẹ̀ ní gbogbo agbáyé yàtọ̀ sí agbègbè Antarctica, ati àwọn ilẹ̀ kéréje-kéréje bíi tìrẹ bíi Ireland, Iceland, Greenland, the [[Hawaiian Islands|Hawaiian archipelago]], àti erékùṣù New Zealand. <ref name=Bauchot>{{cite book|editor=Roland Bauchot|title=Snakes: A Natural History|url=https://archive.org/details/snakesnaturalhis0000bauc|url-access=registration|year=1994|publisher=Sterling Publishing Co., Inc.|location=New York|isbn=978-1-4027-3181-5|page=[https://archive.org/details/snakesnaturalhis0000bauc/page/220 220]}}</ref> Láfikún, àwọn ejò inú òkun ni a lè ri ní àwọn [[odò]] bíi Indian ati Pacific oceans. Lọ́wọ́lọ́wọ́ bayii, oríṣi ìran ejo tí ó ní orílẹ̀ agbáyé ju ogún lọ gẹ́gẹ́ bí àwọn onímọ̀ ti fìdí rẹ̀ múlẹ̀, amọ́ tí wọ́n sì pín sí ọ̀nà ogún ó lé àádọ́ta (520) nígbà tí àyà wọ́n sì jẹ́ 3,900 níye.<ref name="NRDB-Cs">{{cite web|title=Search results for Higher taxa: snake|url=https://reptile-database.reptarium.cz/advanced_search?taxon=snake&submit=Search|url-status=live|archive-url=|archive-date=|access-date=7 March 2021|website=reptile-database.org}}</ref> Àwọn ejò tí a ń sọ nípa rẹ̀ yí yàtọ̀ síra wọn ní ìrísí láti orí tẹ́ẹ́rẹ́ de {{convert|10.4|cm|in|abbr=on|adj=mid|-long}}<ref name="zootaxa"/> ejòlá tí ó le gbé odidi [[ènìyàn]] mì {{convert|6.95|m|ft|sp=us}} in length.<ref name="SunBear">{{cite journal|author=Fredriksson, G. M.|title=Predation on Sun Bears by Reticulated Python in East Kalimantan, Indonesian Borneo|journal=Raffles Bulletin of Zoology|volume=53|issue=1|year=2005|pages=165–168|url=http://dare.uva.nl/document/161117|url-status=live|archive-url=https://web.archive.org/web/20140709001708/http://dare.uva.nl/document/161117|archive-date=2014-07-09}}</ref> Èrò àwọn onímọ̀ sáyéẹ́nsì aṣèwádí ni wípé ìran ejò ni wọ́n ṣẹ̀ láti ara ìran alángbá yálà ní orí ilẹ̀ ni tàbí inú [[omi]]lásìkò ''jùrásíìkì'' tàbí 'Ma''. <ref>{{cite web | last = Perkins | first = Sid | name-list-style = vanc | date = 27 January 2015 | title = Fossils of oldest known snakes unearthed | url = http://news.sciencemag.org/paleontology/2015/01/fossils-oldest-known-snakes-unearthed | website = news.sciencemag.org | access-date = 29 January 2015 | url-status = live | archive-url = https://web.archive.org/web/20150130043614/http://news.sciencemag.org/paleontology/2015/01/fossils-oldest-known-snakes-unearthed | archive-date = 30 January 2015 }}</ref><ref>{{cite journal | vauthors = Caldwell MW, Nydam RL, Palci A, Apesteguía S | title = The oldest known snakes from the Middle Jurassic-Lower Cretaceous provide insights on snake evolution | journal = Nature Communications | volume = 6 | pages = 5996 | date = January 2015 | pmid = 25625704 | doi = 10.1038/ncomms6996 | number = 5996 | bibcode = 2015NatCo...6.5996C | doi-access = free }}</ref>
Púpọ̀ nínú àwọn ìran ejò ni wọn kò ní [[oró ejò]], àwọn tí wọ́n sì ní nínú wọn ma ń sábà lòó láti pa nkan ni tàbí kí wọ́n fi da nkan lágara, amọ́ wọn kìí lo oró wọn láti fi gbe ara wọn níjà. Lara àwọn ejò olóró ni wọ́n lè lo oró wọn láti fi ìjàmbá tàbí kí wọ́n fi oró wọn pa pàá pàá jùlọ ọmọ ènìyàn. Àwọn ejò tí wọn kò ní oró ni wọ́n sábà ma ń gbà nkan mì tàbí kí wọ́n dì mọ́ nkan náà títí yóò fi kú.
 
==Àwọn itọ́ka sí==
{{reflist}}
Jẹ́ kíkójáde láti "https://yo.wikipedia.org/wiki/Ejò"