D. O. Fagunwa: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Content deleted Content added
kNo edit summary
kNo edit summary
Ìlà 1:
{{Infobox writer <!-- For more information see [[:Template:Infobox Writer/doc]]. -->
{{Infobox Person
| honorific_prefix = Chief
| name = Daniel Ọlọ́runfẹ́mi Fágúnwà
| image =
| image_size =
| alt =
| caption =
| pseudonym =
| birth_name = Daniel Oròwọlé Fágúnwà
| birth_date = {{birth year|1903}}
| birth_place = [[Oke-Igbo]], Nigeria
| death_date = {{death date and age|1963|12|07|1903}}
| death_place = [[Bida]], Nigeria
| resting_place = [[Oke-Igbo]], [[Nigeria]]
| occupation = Olùkọ́ èdè [[Yorùbá]] ati ònkọ̀wé ìtàn àròsọ
| spouse = Chief Elizabeth Adébánkẹ Fágúnwà (1932–2018)
| language = [[Yorùbá]]
| period = 1930–1963
| notableworks = ''[[Ògbójú Ọdẹ nínú Igbó Irúnmọlẹ̀]]'' ní ọdún 1938; ''[[Ogboju ode ninu igbo olodumare|Igbó Olódùmarè]]'' in 1949; ''Ìrèké Oníbùdó'' ọdún 1949; ''Ìrìnkérindò nínú Igbó Elégbèje'' ọdún 1954 ''Àdìtú Olódùmarè'' ọdún 1961
| genre = Ìtàn Àròsọ (prose)
| subject =
| movement =
| awards =
| signature =
| signature_alt =
| website =
| portaldisp =
}}
 
'''Daniel Ọlọ́runfẹ́mi Fágúnwà''' tàbí '''D.O. Fágúnwà''' ([[1903]] — [[9 December]], [[1963]]) jẹ́ ònkọ̀wé ọmọ orílẹ̀-èdè [[Nàìjíríà]] tí wọ́n bí ní Òkè-Ìgbò ní ìpínlẹ̀ [[Òndó]]. Ó jẹ́ ògúná gbòngbò ònkọ̀wé [[ìtàn àròsọ]] ní èdè [[ Yorùbá]] ati olùkọ́ èdè Yorùbá nígbà ayé rẹ̀. O je Oguna gbongbo Onkowe itan aroso, bakanaa o tun je oluko [[Ede Yoruba]]. Awon iwe re olokan-o-jokan lo gun opolopo awon onkowe ile Yoruba lonii ni kese ni eyi ti o mu ilosiwaju ba ede Yoruba lapapo.
[[Olóyè]] '''Daniel Oròwọlé Ọlórunfẹ́mi Fágúnwà''' [[Order of the British Empire|MBE]] (1903 – 7 December 1963), tí gbogbo ènìyàn mọ̀ sí '''D. O. Fágúnwà''', Ó jẹ́ ògúná gbòngbò tí dá [[ìtàn àròsọ]] ní èdè [[ Yorùbá]] sílẹ̀, ati olùkọ́ èdè Yorùbá nígbà ayé rẹ̀..<ref>{{Cite web|title=Fagunwa wrote his first novel in the bush|url=https://www.vanguardngr.com/2016/06/fagunwa-wrote-first-novel-bush/|date=2016-06-17|website=Vanguard News|language=en-US|access-date=2020-05-24}}</ref>
 
==Ìgbé ayé rẹ̀==
Wọ́n bí Fágúnwà ní ìlú [[Òkè-Ìgbò]], ní [[Ìpínlẹ̀ Òndó]]. Bàbá rẹ̀ ni ọ̀gbẹ́ni Joshua Akíntúndé Fágúnwà nígbà tí ìyá rẹ ń jẹ́ Rachel Òṣunyọmí Fágúnwà.<ref>{{Cite web|title=The Novel of D.O Fagunwa - A commentary by Ayo Bamgbose|url=https://www.sunshinenigeria.com/the-novel-of-do-fagunwa---a-commentary-by-ayo-bamgbose|website=www.sunshinenigeria.com|language=en|access-date=2020-05-27}}</ref> Bàbá bàbá re ni Fáníyì Arójò, tí ó jẹ́ jagun-jagun. Ọmọ ọmọ Fa ni yi yí ni Égúnṣọlá Asungaga Bèyíokú, tí ó jẹ́ adífálà ní ìlú Origbo, ìlú tí ó wà ní ẹ̀gbẹ́ ìlú [[Ipetumodu]]. Nígbà tí Ìyá ìyá rẹ̀ ń jẹ Ṣayọadé Olówu, tí ó jẹ́ ọ̀kan nínú ọmọ bíbí [[Òwú]] ṣáájú kí wọ́n tí gbéra lọ sí ìlú [[Abẹ́òkúta]]. Asungaga yí ni ó kò lọ sí ìlú [[Ilé-Ifẹ̀]] látàrí bí [[Àbíkú]], bí ó tilẹ̀ jẹ́ wípé òun gan gan fúnra rẹ̀ náà jẹ́ [[Àbíkú]] . Nígbà tí ó dé ìlú Ilé-Ifẹ̀ ní àárín ọdún 1870,Ó di [[Oníṣègù]] àti [[Babaláwo]] fún Ọba [[Ọọ̀ni]] ti Ilé-Ifẹ̀ Ọlọ́gbẹ́nlá.
Kẹ́yìn tí ogun Ifẹ́ ati Òndó parí, púpọ̀ nínú àwọn jagun-jagun ni wọ́n pàgọ́ sí [[Abúlé]] kan tí wọ́n ń pè ní "Oko-igbó" tí ó di ''Òkè-Ìgbò'' nísìín. Asungaga bí ọmọ padà bí ọmọ mẹ́rin tí wọ́n gbẹ̀yìn rẹ̀. Àwọn ni: Ifatosa, Akintunde Fagunwa ( tí ó padà yí orúkọ rẹ̀ padà sí Joshua), Ifabunmi àti "Philip" Odugbemi.
 
Àwọn òbí Fágúnwà mú àṣà àti ìṣe [[Yorùbá]] ṣáájú kí wọ́n tó dara pọ̀ mọ́ ẹ̀sì Krìstẹ́nì láàrín ọdún 1910 sí ọdún 1920. Orúkọ abísọ rẹ̀ ni Oròwọlé tí ó sì yí orúkọ rẹ̀ padà sí Ọláọ́runfẹ́mi nígbà tí àwọn òbí rẹ̀ yí sí ẹ̀sìn Krìstẹ́nì. <ref>{{Cite web|title=D.O. Fagunwa {{!}} Nigerian author|url=https://www.britannica.com/biography/D-O-Fagunwa|website=Encyclopedia Britannica|language=en|access-date=2020-05-27}}</ref>. Òun nìkan ni ọmọ ọkùrin tí tó kẹ́yìn àwọn òbí rẹ̀ pẹ̀lú obìnrin mẹ́ta.
 
== Ètò ẹ̀kọ́ rẹ̀ ==
Fágúnwà kẹ́kọ́ ní ilé-ẹ̀kọ́ St. Luke's School,[[Òkè-Ìgbò]], ati ilé-ẹ̀kọ́ St. Andrew's College, ní [[Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́]], ṣáájú kí ó tó di olùkọ́. <ref>{{Cite web|title=D.O. Fagunwa {{!}} Nigerian author|url=https://www.britannica.com/biography/D-O-Fagunwa|website=Encyclopedia Britannica|language=en|access-date=2020-05-27}}</ref>
 
== Iṣẹ́ rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí oniọ̀wé==
Fágúnwà kópa nínú ìdíje tí Ministry of Education gbé kalẹ̀ ní ọdún 1938, ìdíje yí ni ó fàá tí ó fi kọ ìwé ìtàn àròsọ ọlọ́rọ̀ geere ''[[Ògbójú Ọdẹ nínú Igbó Irúnmọlẹ̀]]'', <ref>{{Cite web|title=Fagunwa wrote his first novel in the bush|url=https://www.vanguardngr.com/2016/06/fagunwa-wrote-first-novel-bush/|date=2016-06-17|website=Vanguard News|language=en-US|access-date=2020-05-27}}</ref>. Ìwé yí ni wọ́n fìdí rẹ̀ múlẹ̀ wípé òun ni ìwé ìtàn àròsọ ọlọ́rọ̀ geere akọ́kọ́ tí wọ́n kọ́kọ́ kọ ní èdè [[Yorùbá]] , ati ìwé ìwé ìtàn àròsọ ọlọ́rọ̀ geere anọ́kọ́ ní èdè ilẹ̀ Adúláwọ̀. Ọ̀jọ̀gbọ́n [[Wọlé Ṣóyínká]] ṣe ògbufọ̀ ìwé yí sí èdè Gẹ̀ẹ́sì ní ọdún 1968, tí ó pe ní ''The Forest of A Thousand Demons'',ìwé tí wọ́n gbé jáde láti ọwọ́ ilé-iṣẹ́ itẹ̀wé ''' Random House''' àti ''' City Lights''' ní ọdún 2013 ({{ISBN|9780872866300}}).
Lára àwọn ọ̀gọ̀ọ̀rọ̀ iṣẹ́ ọwọ́ Fágúnwà tún ni: ''[[Ogboju ode ninu igbo olodumare|Igbó Elédùmarè]]'' (''The Forest of God'', 1949), ''Ìrèké Oníbùdó'' (1949), ''Ìrìnkèrindò nínú Igbó Elégbèje'' (''Expedition to the Mount of Thought'', 1954), àti ''Àdìtú Olódùmarè'' (1961).<ref>{{cite web|title=D. O. Fagunwa|url=http://www.britannica.com/EBchecked/topic/200205/DO-Fagunwa|work=Encyclopædia Britannica|accessdate=3 January 2012}}</ref>
 
Fagunwa's novels draw heavily on [[Folklore|folktale]] traditions and idioms, including many [[supernatural]] elements. His heroes are usually Yoruba hunters, who interact with kings, sages, and even gods in their quests. Thematically, his novels also explore the divide between the Christian beliefs of Africa's [[colonialism|colonizers]] and the continent's traditional religions. Fagunwa remains the most widely read Yorùbá-language author, and a major influence on such contemporary writers as [[Amos Tutuola]].<ref>{{cite book|last=Okpewho|first=Isidore|authorlink=Isidore Okpewho|title=African Oral Literature: backgrounds, character, and continuity|year=1992|publisher=Indiana University Press|isbn=0-253-34167-1|page=305}}</ref><ref>{{cite book| last=Gikandi|first=Simon|authorlink=Simon Gikandi|title=Encyclopedia of African Literature|year=2003|publisher=Taylor & Francis|isbn=0-415-23019-5|pages=252–255}}</ref> He also used Greek myths and Shakespearean stories as themes in his books, such as in his book [[Igbo Olodumare]], where the character Baba-onirugbon-yeuke tells a story similar to Romeo and Juliet.
 
D. O. Fagunwa was the first Nigerian writer to employ folk philosophy in telling his stories.
 
Fagunwa was awarded the [[Margaret Wrong Prize]] in 1955 and was made a [[Member of the Order of the British Empire]] in 1959. He died in a river in 1963; the ground by the bank of the river apparently gave way under his feet and he fell into the river. He tried to swim out of the water but sank because the canoe by the river also fell and collapsed on him.<ref>''Nigerian Punch'' newspaper, 12 August 2013 edition.</ref><ref>[http://www.vanguardngr.com/2016/06/fagunwa-wrote-first-novel-bush/ "Fagunwa wrote his first novel in the bush"], ''Vanguard'' (Nigeria), 18 June 2016.</ref><ref>{{Cite web|title=D.O. Fagunwa|url=https://www.goodreads.com/author/show/6928208.D_O_Fagunwa|website=www.goodreads.com|access-date=2020-05-27}}</ref>
 
==Legacy==
Fagunwa Memorial High School and Fagunwa Grammar School in [[Oke-Igbo]], Nigeria, are named for Fagunwa. His daughter, Yejide Ogundipe, serves as a council chairperson for [[Ile Oluji/Okeigbo]]. Fagunwa day (formerly known as Fagunwa night) is an annual event aimed at reading and promoting his five books. Fagunwa day was initiated in his honour by the Society of Young Nigerian Writers in conjunction with Fagunwa Literary Society and [[Egbe Omo Oduduwa|Egbe Odo]] Onkowe Ede Yoruba.
 
==Academic works about Fagunwa's writings==
*Olaleru, Olanike. "Oral Performance Techniques in the Works of D. O. Fágúnwà." ''Ibadan Journal of English Studies'' 7 (2018): 361-374.
 
==References==
{{reflist}}
 
{{Authority control}}
 
{{DEFAULTSORT:Fagunwa, Daniel O.}}
[[Category:1903 births]]
[[Category:1963 deaths|Fagunwa, Daniel O.]]
[[Category:Nigerian speculative fiction writers|Fagunwa, Daniel O.]]
[[Category:Members of the Order of the British Empire]]
[[Category:Yoruba writers]]
[[Category:Nigerian male novelists]]
[[Category:20th-century Nigerian novelists]]
[[Category:Yoruba-language writers]]
[[Category:Writers from Ondo State]]
[[Category:Nigerian folklorists]]
[[Category:Deaths by drowning]]
[[Category:20th-century male writers]]
 
 
 
 
 
 
 
'''Daniel Ọlọ́runfẹ́mi Fágúnwà''' tàbí '''D.O. Fágúnwà''' ([[1903]] — [[9 December]], [[1963]]) jẹ́ ònkọ̀wé ọmọ orílẹ̀-èdè [[Nàìjíríà]] tí wọ́n bí ní Òkè-Ìgbò ní ìpínlẹ̀ [[Òndó]]. Ó jẹ́ ògúná gbòngbò ònkọ̀wé [[ìtàn àròsọ]] ní èdè [[ Yorùbá]] ati olùkọ́ èdè Yorùbá nígbà ayé rẹ̀. O je Oguna gbongbo Onkowe itan aroso, bakanaa o tun je oluko [[Ede Yoruba]]. Awon iwe re olokan-o-jokan lo gun opolopo awon onkowe ile Yoruba lonii ni kese ni eyi ti o mu ilosiwaju ba ede Yoruba lapapo.
 
==Àwọn ìwé tó kọ==