Genevieve Nnaji: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Content deleted Content added
No edit summary
Àwọn àlẹ̀mọ́: Àtúnṣe ojú fóónù Àtúnṣe ojú fóónù Advanced mobile edit
kNo edit summary
Ìlà 7:
| occupation = Òṣèré, Aṣoge, Akọrin
}}
'''Genevieve Nnaji''' ({{pron-en|n'nɑːdʒɪ}},<ref>[http://www.youtube.com/watch?v=2xcgLJxlg_4 Movie trailer calling Nnaji's name at 2:36 into the trailer]</ref> (tí wọ́n bí ní Ọjọ́ kẹta oṣù karùn-ún ọdún 1979) jẹ́ ọmọ ìlú '''Mbaise'''[[Ìpínlè Ímò]], lórílẹ̀-èdè [[Nàìjíríà ]]),<ref>[http://hollywood.premiere.com/movie_stars/celebrity-Genevieve+Nnaji Genevieve Nnaji, Date of Birth]</ref> jẹ́ òṣeré sinima-agbelewo ọmọ ilẹ̀ [[Nàìjíríà]]. Ní ọdún 2005, ó gba Ẹ̀bùnẹ̀bùn ''Akedẹ́mì sinimá-àgbéléwò ilẹ̀ Áfíríkà'' gẹ́gẹ́ bí Òṣeré-bìnrin tó dárajùlọ.<ref name=info1>[http://www.newstimeafrica.com/archives/1007 Africa’s Most Famous Movie Star?]</ref>
 
==Ìgbà èwe rẹ̀==
Ìlú [[Èkó]] ni Genevieve Nnaji ti dàgbà. ÌkẹrinÒun ni àbílékẹrin [[ọmọ]] nínú àwọn ọmọ méjọ tí òbí rẹ̀ bí, ọ̀mọ̀wé ni àwọn òbí rẹ̀. Bàbá rẹ̀ siṣẹ́ gẹ́gẹ́ bíi onímọ̀ iṣẹ́-ẹ̀rọ (engineer) nígbàtí ìyá rẹ̀ sì jẹ́ olùkọ́. Ò lọ sí ilé ẹ̀kọ́ Methodist Girls College ní ìlú Yaba, lẹ́yìn rẹ̀ ó tẹrísíwọlé sí ilé-ẹ̀kọ́ [[ Fàsítì ìlú Èkó]]. Níbẹ̀ lówà tó ti bẹ̀rẹ̀ sí ń ṣiṣẹ́ díèdíẹ̀díẹ̀ díẹ̀ gẹ́gẹ́ bíi òṣèré ni [[Nollywood]].<ref name=info1/>
 
==Iṣẹ́ ọwọ́==