Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò "Adegoke Adelabu"

946 bytes added ,  07:56, 30 Oṣù Kàrún 2021
k
Kò sí ìsọníṣókí àtúnṣe
k (Bot: Migrating 1 interwiki links, now provided by Wikidata on d:q4681515 (translate me))
k
{{short description|Nigerian politician (1915–1958)}}
'''Gbadamosi Adegoke Adelabu''' (September 3, 1915 – March 20, 1958) je oloselu omo orile-ede [[Naijiria]].
{{Infobox officeholder
 
| name = Adegoke Adelabu
Baba re ni Sanusi Ashiyanbi Adeyege Adelabu; iya re ni Awujola Ajoke
| image = Adelabu.jpg
 
| alt =
{{ẹ̀kúnrẹ́rẹ́}}
| order = Opposition Leader
==Itokasi==
| office = Western House of Assembly
{{Reflist}}
| term_start = 1956
[http://books.google.com/books?id=djE9AAAAIAAJ&pg=PA26&lpg=PA26&dq=baale+fijabi+ibadan+treaty&source=bl&ots=7DFclaHdRX&sig=kmt7e2MwsfbREHg_DxLLLMxGJTI&hl=en&ei=6FkZTcPOIYKY4AbyuLyGAg&sa=X&oi=book_result&ct=result&resnum=9&sqi=2&ved=0CEYQ6AEwCA#v=onepage&q&f=false Biography]
| term_end = 1958
{{DEFAULTSORT:Adelabu Adegoke}}
| lieutenant =
[[Ẹ̀ka:àwọn ọjọ́ìbí ní 1915]]
| order2 = Chairman of Ibadan District Council
[[Ẹ̀ka:Àwọn ọjọ́aláìsí ní 1958]]
| term_start2 = 1954
[[Ẹ̀ka:àwọn olóṣèlú ará Nàìjíríà]]
| term_end2 = 1956
| order3 = Federal Minister of Natural Resources and Social Services
| term3 = January 1955 - January 1956
| birth_date = 3rd september 1915
| birth_place = Ibadan
| death_date = March 25, 1958(Age 42)
| death_place =
| spouse =
| party = [[National Council of Nigeria and the Cameroons|NCNC]]
| signature =
| signature_alt =
}}
'''Gbàdàmọ́sí Adégòkè Adélabú''' tí a bí ní ọjọ́ Kẹta osù Kẹsàn an ọdún 1915 ní ìlú [[Ìbàdàn]] ní orílẹ̀-èdè [[Nàìjíríà]] jẹ́ olóṣèlú àti Mínísítà tẹ́lẹ̀ ohun àlùmọ́nì ati ìgbáyé-gbádùn fún orílẹ̀-èdè Nàìjíríà láàrín osù Kínní ọdún 1955 sí oṣù Kínní ọdún 1956, tí ó sì padà di olórí alátakò ní ilé ìgbìmọ̀ọ̀ aṣòfin ní ẹkún ìjọba Ìwọ̀ Oòrùn nígbà ayé rẹ̀. Ó di ìlú-mòọ́ká látàrí akitiyan ati ipa malegbagbe tí ó kò nínú ìṣèlú orílẹ̀-èdè [[Nàìjíríà]].
Adélabú lọ sí ilé-ẹ̀kọ́ [[Government College, Ibadan]] ó sì di oníṣòwò lẹ́yìn ẹ̀kọ́ rẹ̀. Ó pàdánù ẹ̀mí rẹ̀ sínú ìjàmbá ọkọ̀ lẹ́yìn ìgbà diẹ̀ tí orílẹ̀-èdè [[Nàìjíríà]] gba òmìnira lọ́wọ́ ìjọba àmúnisìn Brítènì.
{{sfn|Sklar|p=303}}