Ìran Yorùbá: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Content deleted Content added
No edit summary
#WPWPKWR
Ìlà 21:
|related-c= [[Ìran Ẹdó]], [[Tapa]], [[Igala]], [[Itsekiri]], [[Ìgbìrà]]
}}
 
'''Ìran Yorùbá''' tabi '''Àwọn ọmọ Yorùbá''' jé árá ìpinle ẹ̀yà ila ọ́wọ́ òsi ní orílẹ̀ Áfríkà. Wọn jé árá ìpin àwọn ìran to pò ju ní orílẹ̀ Áfríkà. [[Ilẹ̀ Yorùbá]] ní púpò nínú wọ́n. Ẹ lè ri wọ́n ní ìpínlẹ̀ púpò bíi [[ìpínlẹ̀ Ẹdó]], [[Ìpínlẹ̀ Èkìtì]], [[Èkó|ìpínlẹ̀ Èkó]], [[Ìpínlẹ̀ Kwara]], [[ìpínlẹ̀ Kogí]], [[ìpínlẹ̀ Ògùn]], [[Ìpínlẹ̀ Òndó|Ìpínlẹ̀ Oǹdó]], [[ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun]], [[ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́]], àti ní ẹ̀yà ila ọ́wọ́ òsi ti ilè Nàìjíríà. Ẹ tún le rí wọ́n ní ìpínlẹ̀ to wa nínú orílẹ̀-èdè Olómìnira Benin ([[Benin|Dahomey]]), ní orílẹ̀-èdè Sàró ([[Sierra Leone]]), àti ní àwọn orílẹ̀-èdè miiran bíi àwọn tí wọ́n pè ní [[Togo]], [[Brazil]], [[Cuba]], [[Haiti]], [[United States of America|Amẹ́ríkà]] ati Venezuela. Àwọn Yorùbá wà l'árá àwọn to tóbí ju ní [[Nàìjíríà|ilè Nàìjíríà]]. Ó le jẹ́ pe àwọn lo tóbí ju, abí àwọn lo jẹ́ ikejì, abi àwọn lo jẹ́ ikẹ́tá.