Adó-Èkìtì: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Content deleted Content added
kNo edit summary
Àwọn àlẹ̀mọ́: Àtúnṣe ojú fóónù Àtúnṣe ojú fóónù Advanced mobile edit
Ìlà 133:
* Fresh FM, tí ó jẹ́ ti gbajú-gbajà olórin ẹ̀mí [[Yínká Ayéfẹ́lẹ́]].
Oríṣiríṣi ohun ọrọ̀ aje ni ó wà ní ìlú Adó, tí àwọn [[ènìyàn]] sì ṣòwò kárà-kátà ohun ọ̀gbìn oríṣiríṣi bíi: [[ẹ̀gẹ́]], [[iṣu]], àwọn nkan oníhóró lóríṣirí, [[tábà]] [[òwú]] tí wọ́n sì ma ń ṣe iṣẹ́ [[aṣọ]] híhun àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ. {{Citation needed|date=May 2020}}
 
 
==Ètò ìṣèjọba ìbílẹ̀==
Lọ́wọ́ lọ́wọ́, ẹni tí ó jẹ́ adarí ìbílẹ̀ pàtàkì akọ́kọ́ ní ìlú Adó ni [[Ọba]] tàbí '''Èwí Adó''' ni [[Rufus Aladesanmi III]] tí wọ́n jẹ́ ''Èwí ti Adó'', tí wọ́n tẹ́rí gbadé lẹ́yì Èwí àná, Ọba ''Samuel Adeyemi George-Adelabu I'' ní ọdún 1990.
 
==Àwọn Itọ́ka sí==