Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò "Nnamdi Azikiwe"

332 bytes added ,  04:20, 3 Oṣù Kẹ̀wá 2009
Kò sí ìsọníṣókí àtúnṣe
 
==Ìgbà èwe==
A bí Azikiwe ní ojo 16 osu kokanla ọdún 1904 ni [[Zungeru]], apaariwani apa ariwa Naijiria botile jepe awon obi re je Ígbò lati apa ilaoorun Naijiria. Nnamdi tumosi "baba mi wa laaye." Leyin eko re Methodist High School ni [[Èkó]] o gbera lo si ile [[USA|Amerika]]. Nibe o ka we ni [[Yunifasiti Howard]] ni [[Washington, D.C.]] ko to di pe o pari eko re ni [[Yunifasiti Lincoln]] ni [[Ipinle Penssylvania]] ni 1930. Ó kàwé ní calabar àti [[Èkó]]. Òun ni olóòtu, Morning Post West African Pilot. Ó di ènìyàn dúdú àkọ́kọ́ tí yóò je Gomina-Gbogbogbo fun [[Nigeria]] ní 1960. Ó se ìdásílè University of Nsukka. Ó kú ní odún 1996.