Èdè: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Content deleted Content added
k replacing Unicode code points from the private range (U+E000 to U+F8FF) by the proper combining accents
No edit summary
Ìlà 1:
[[File:Short oral history of Ede in Ede language by a native speaker (non-subtitled).webm|thumb|Ìtàn ṣókí nípa Ède láti ẹnu ọmọ bíbí ìlú Ede]]
 
Oríṣìíríṣìí àwọn Onímọ̀ ní ó ti gbìnyànjú láti fún èdè ní oríkì tàbí òmíràn ṣùgbọ́n kí a tó bẹ̀rẹ̀ sí ń ṣe àgbéyẹ̀wò àwọn oríkì wònyìí, èmi pàápàá yóò gbìnyìnjú láti sọ lérèfé ohun tí èdè túmọ̀ sí.
Èdè ní í ṣe pẹ̀lú ọ̀nà ìbánisọ̀rọ̀ tí àwọn ènìyàn ń lò ní àwùjọ báyá fún ìpolówó ọjà, ìbáraẹni sọ̀rọ̀ ojoojúmó, ètò ìdílé tàbí mọ̀lẹ́bí àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ.
Jẹ́ kíkójáde láti "https://yo.wikipedia.org/wiki/Èdè"