Èdè: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Content deleted Content added
kNo edit summary
No edit summary
Ìlà 4:
Èdè níí ṣe pẹ̀lú ọ̀nà ìbánisọ̀rọ̀ tí àwọn ènìyàn ń lò ní àwùjọ yálà fún ìpolówó ọjà, ìbáraẹni sọ̀rọ̀ ojoojúmó, ètò ìdílé tàbí mọ̀lẹ́bí àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ. <ref name="www.dictionary.com 2019">{{cite web | title=Definition of language | website=www.dictionary.com | date=2019-10-15 | url=https://www.dictionary.com/browse/language | access-date=2021-07-20}}</ref>
Gẹ́gẹ́ bí ó ti sọ, ó ní: èdè''Èdè jẹ́ gẹ́gẹ́ bí ọ̀nà ìrú kan gbòógì tí àwùjọ àwọn ènìyàn ń lò láti fi bá ara ẹni sọ̀rọ̀''.
Raji (1993:2) pàápàá ṣe àgbékalẹ̀ oríkì èdè ó ṣàlàyé wípé;
“Èdè ni ariwo tí ń ti ẹnu ènìyàn jáde tó ní ìlànà. Ìkíní lè ní ìtumọ̀ kí èkeji maa ní. Èdè máa ń yàtọ̀ láti ibìkan sí òmíràn. Ohun tó fà á ni pé èdè kọ̀ọ̀kan ló ní ìwọ̀nba ìrú tó ń mú lò. Èdè kankan ló sì ní ìlànà tirẹ̀ to ń tèlé.”
Wardlaugh sọ nínú Ogusiji et al (2001:10) wí pé,: “Èdè ni ni àwọn àmì ìsọgbà tí ó ní ìtumọ̀ tí o yàtọ̀ tí àwọn ènìyàn ń lò láti fi bá ara wọn sọ̀ọ̀.”
“Language is a System of arbitrary Vocal Symbols use for human Communication.”
“Èdè ni ni àwọn àmì ìsọgbà tí ó ní ìtumọ̀ tí o yàtọ̀ tí àwọn ènìyàn ń lò láti fi bá ara wọn sọ̀ọ̀.”
Àwọn Oríkì yìí àti ọ̀pọ̀lọpọ oríkì mìíràn ni àwọn Onímọ̀ ti gbìyànju láti fún èdè, kí a tó lè pe nǹkan ní èdè, ó gbọ́dọ̀ ní àwọn èròja wọ̀nyí: èdè gbọ́dọ̀ jẹ́:
 
Line 63 ⟶ 61:
(3) Wọn kì í sì í ní Ìtumọ̀
 
Pẹ̀lú gbogbo àwọn nǹkan tí mo ti sọ nípa ìyàtọ̀ tó wà láàrín èdè [[ènìyàn]] àti [[ẹranko]], Ó hàn gbangba wípé a kò le è fi èdè ẹranko àti ti ènìyàn wé ara wọn.
[[Yorùbá]] bì wọ́n ní “igi ímú jìnà sí ojú, bẹ́ẹ̀ a kò leè fi ikú wé oorun. Bẹ́ẹ̀ gẹ́gẹ́ ni èdè ènìyàn àti ẹranko rí. Nínú èdè ènìyàn lati rí gbólóhùn tí ènìyàn so jáde tí a sì leè fi ìmò ẹ̀dá èdè fó sí wéwé. Àtiwípé àǹfàní káfi èdè lu èdè kò sí ní àwùjọ ẹranko gẹ́gẹ́ bí i ti ènìyàn. Fún bí àpẹẹrẹ.
Olu ra ìṣu
Olú nínú gbólóhùn yìí jẹ́ ọ̀rọ̀-Orúkọ ní ipò Olùwá, rà jẹ́ Ọ̀rọ̀-ìṣe nígbà tí ísu jẹ́ ọ̀rọ̀ orúkọ ní ipò ààbọ̀.
Line 70 ⟶ 68:
Nítorí náà èdè ènìyàn yàtọ̀ sí enà apẹẹrẹ, ìfiyèsí (Siganl Code) àwọn ẹranko.
 
==Àwọn Ìwé àmúlò==
Àwọn ìwé ìtọ́ka sí ni àwọn wọ̀nyìí.
 
Fatusin, S.A (2001), An Introduction to the Phonetics and Phonology of English. Green-Field Publishers, Lagos.
Jẹ́ kíkójáde láti "https://yo.wikipedia.org/wiki/Èdè"