Akinola Deko: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Content deleted Content added
No edit summary
kNo edit summary
Ìlà 1:
{{Infobox officeholder|name=Gabriel Akinola Deko|image=Gabriel Akintola Deko (right) and David Ben-Gurion in Jerusalem, 1958.jpg|caption=Gabriel Akinola Deko with Israeli Prime Minister [[David Ben-Gurion]] in [[Jerusalem]], 1958|title=Regional Minister for Agriculture|term_start=1957|term_end=1963|predecessor=[[Augustus Akinloye]]|successor=[[Sanya Onabamiro]]|title2=|term_start2=|term_end2=|predecessor2=|successor2=|title3=|term_start3=|term_end3=|predecessor3=|successor3=|title4=|term_start4=|term_end4=|predecessor4=|successor4=|birth_date=30 October 1913|birth_place=[[Idanre]], [[Nigeria]]|death_date=5 November 1987|death_place=London, England|party=Action Group, [[National Party of Nigeria]]|residence=[[Ibadan]], Nigeria|spouse=Chief (Mrs) Caroline Ebun Akin-Deko|profession=[[Building contractor]]|footnotes=}}
'''Gabriel Akinọlá Dèkó''' tí wọ́n bí í ọjọ́ kaẹ́dọ́gbọ̀n oṣù Kẹwàá, ọdún 1913( 30-1-1913) tí ó sì kú ní ọjọ́ Kárùún oṣù Kọkànlá , ọdún 1987 ( 5 November 1987).<ref name="GCI Museum">{{cite web | title=Gabriel Akinola Deko | website=GCI Museum | url=http://www.gcimuseum.org/tags/gabriel-akinola-deko | access-date=2019-10-07}}</ref>Ni ó jẹ́ oní kọ̀ngílá ìṣẹ́ Ẹ̀kọ́lé àti Mínísítà fún ètò ọ̀ aètò ọ̀gbìn nígbà kan rí apá Ìwọ̀ Oòrùn ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, Ó tún jẹ́ ọ̀rẹ́ tímọ́ tímọ́ fún Olóyè [[Ọbáfẹ́mi Awólọ́wọ̀|Awólówọ̀]]. Gẹ́gẹ́ bí Mínísítà, ó kópa ribiribi nípa mímú ìlọsíwájú bá ètò ìgbnisíṣẹ́ àwọn àṣẹ̀sẹ̀ yọ ọ̀gọ́mọ̀ tí wọ́n kàwé jáde ní Unifásitì tí wọ́n sì nífẹ̀ẹ́ sí iṣẹ́ àgbẹ̀ tí ìjọba yóò ma kọ́ wọn ní iṣẹ́ ọ̀gbìn ní àwọn ìletò tí wọ́n ti kọ́ kalẹ̀ fún iṣẹ́ àkànṣe náà tí ìjọba yóò sì ma fún wọn ní owó ọ̀yà. Àwọn akẹ́ọ̀ọ́ náà yóò ma ṣiṣẹ́ f ọ̀gbìn . Dídá àwọn ìletò wọ́nyí ni wọ́n jẹ́ ètò àyálò láti ọ̀dọ àwọn [[Ísráẹ́lì|Israeli]] . Ètò yí wà fún láti já ọkàn àwọn Ọ̀dọ́-langba kúrò nínú èrò wíwáṣẹ́ lọ sí àwọn ìlú ńlá ńlá tí wọ́n sì yan iṣẹ́ àgbẹ̀ ní pọ̀sìn.<ref name="Ibadan Insider 2016">{{cite web | title=OBASANJO VISITS THE AKIN-DEKO FAMILY IN IBADAN | website=Ibadan Insider | date=2016-06-17 | url=https://www.ibadaninsider.com/uncategorized/obasanjo-visits-the-akin-deko-family-in-ibadan/ | access-date=2019-10-07}}</ref>
Akin Dèkó ni wọ́n bí ní ìlú igbotu, ní [[Ìpínlẹ̀ Òndó]], tí àwọn òbí rẹ̀ sì jẹ́ ọmọ ìlú Ìdànrè ní Ìpínlẹ̀ Òndó kan náà. Ó lọ sí ilé-ẹ̀kọ́ St Peters,ní [[Èkó|Ìpínlẹ̀ Èkó]], fún ètò ẹ̀kọ́ Alákùkọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀ àti ti ìpele ọlọ́dún mẹ́fà ẹlẹ́ẹ̀kejì, Ó tún lọ sí Government College [[Ìbàdàn]] (GCI), Ó sì parí ẹ̀kọ́ kíkà rẹ̀ ní ilé-ẹ̀ ẹ̀kọ́ [[Yábàá College|Yaba Higher College]] ní Ìpínlẹ̀ Èkó níbi tí ó ti gba ìwé-ẹ̀rí nínú ẹ̀kọ́ Olùkọ́ . Ó bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ Olùkọ́ ní ilé-ẹ̀ọ́ rẹ̀ tí ó ti jáde tẹ́lẹ̀ (Government College, Ìbàdàn) tí ó sì ń kọ́ ni nípa ìmọ̀ ẹ̀rọ àti ṣíṣàmúlò Ìṣirò (mechanics and applied mathematics). Lẹ́yìn ìgbà díẹ̀, ó yan iṣẹ́ ikọ́lé láàyò tí ó sì gb ilé-ẹ̀kọ́ ìkọ́lé Brixton lọ ní ìlú London. Kò pẹ́ púpọ̀ tí ó fi bẹ̀rẹ̀ ilé-iṣẹ́ ìkọ́lé tirẹ̀ náà. Ní ọdún 1950s, ọ̀rẹ́ rẹ̀ ba sọ̀rọ̀ wípé kí ó dara pọ̀ mọ́ òṣèlú ní ọdún 1956, Ó gba imọ̀ràn ọ̀rẹ́ rẹ̀, lọ́gán tí ó sì dara pọ̀ mọ́ òṣèlú ni ó wọlé ìdìbò tí ó sọọ́ di Mínísítà fún ètò Ọ̀gbìn apá Ìwọ̀-Oòrùn ilẹ̀ Nàìjíríà.
<ref name="Google Books">{{cite web | title=International Law Reports | website=Google Books | url=https://books.google.com/books/about/International_Law_Reports.html?id=2HY2p0JX-30C | access-date=2019-10-07}}</ref>Akinọlá ni ó ṣe aṣojú fún ilẹ̀ [[Nàìjíríà]] níbi àpérò fún Óńjẹ àti Nnkan irè-Oko([[Àgbájọ fún Oúnjẹ àti Iṣẹ́àgbẹ̀|Food and Agriculture Organization)]] ní ilẹ̀ Adúláwọ̀. Wọ́n tún fi ṣe ìgba-kejì Gíwá ilé-ẹ̀kọ́ fún ilé-ẹ̀kọ́ [[Yunifásítì Tẹknọ́lọ́jì Àpapọ̀ ilú Àkúrẹ́|Federal University of Technology, Àkúrẹ́]] . Òun náà tún ni igbákejì Gíwá ilé-ẹ̀kọ́ [[Yunifásítì ìlú Ìbàdàn|University of Ìbàdàn]] [[Yunifásítì ìlú Benin|àti University of Benin]].<ref name="The Guardian Nigeria News - Nigeria and World News 2015">{{cite web | title=Reminiscences On A Great Academician: Prof. Albert Ilemobade | website=The Guardian Nigeria News - Nigeria and World News | date=2015-07-26 | url=https://m.guardian.ng/sunday-magazine/reminiscences-on-a-great-academician-prof-albert-ilemobade/ | access-date=2019-10-07}}</ref>