Eyín: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Content deleted Content added
Ṣ'èdá ojúewé pẹ̀lú "{{About}} {{pp-semi|small=yes}} thumb|right|200px|A [[Common chimpanzee|chimpanzee displaying its teeth]] '''Eyín''' jẹ..."
 
kNo edit summary
Ìlà 3:
[[File:Close up - chimpanzee teeth.png|thumb|right|200px|A [[Common chimpanzee|chimpanzee]] displaying its teeth]]
 
'''Eyín''' jẹ́ ẹ̀yà ara kan tí ó le koko tí kìí rọ̀ tí ó ma ń ju jáde láti inú [[erìgì]] nínú ẹnu tí a ma ń lò láti jẹun tàbí fọ́ egungun. Gbogbo eranko tí ó ní egungun lẹ́yìn tí wọ́n sì ma ń rún ónjẹ lẹ́nu ni wọ́n ma ní eyín. Nígbà tí p7pọ̀ nínú wọn ma ń fi eyin ṣọdẹ tàbí dáàbò bo ara wọn lọwọ́ ewu. Àwọn onímọ̀ fìdí rẹ̀ múlẹ̀ wípé eyín kìí ṣe egungun rárá bí ó ti wulẹ̀ kí ó mọ, amọ́ eyín jẹ́ àkójọ pọ̀ àwọn tíṣù kan tí wọ́n ń pè ní '''ectoderm''' ni wọ́n para pọ̀ di eyín.
==Híhù eyín láàrín àwọn ẹranko==
Híhù eyín láàrín àwọn ẹranko elégungun ma ń sábà jẹ́ bá ká ń náà, àmọ́ ìyàtọ̀ ma ń wà láàrín ipò àti bí wọ́n ṣe ń hù láàrín ẹranko sí ẹranko. Kìí ṣe àwọn ẹranko nikan ni ó ma ń hu eyín, àwọn ẹja àti ẹran inú omi náà ma ń hu eyín.
Jẹ́ kíkójáde láti "https://yo.wikipedia.org/wiki/Eyín"