Ìjẹ̀bú: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Content deleted Content added
No edit summary
Ìlà 2:
 
==Ìtàn ìṣẹ̀dálẹ̀ Ìjẹ̀bú==
[[Fáìlì:Short_oral_history_of_Ijebu_in_Ijebu_dialect_by_a_native_speakerShort oral history of Ijebu in Ijebu language by a native speaker.webm|thumb|Ìtàn ṣókí nípa Ijebu láti ẹnu ọmọ bíbí ìlú Ijebu]]
Ajẹbú àti Olóde jẹ́ ọdẹ. Gẹ́gẹ́ bí wọ́n ti sọ, níbi tí ẹnìkọ̀ọ̀kan wọn ti ń dẹ igbó kiri ni wọ́n ti pàdé ara wọn nínú igbó.
Báyìí ni wọ́n ṣe di ọ̀rẹ́ tímọ́tímọ́. Ní ọjọ́ kan, wọ́n dá ìmọ̀ràn láàrin ara wọn pé ó yẹ kí wọ́n dá ibìkan sílẹ̀ tí àwọn yóò fi ṣe ìbùgbé lẹ́yìn tí wọ́n bá ṣe ọdẹ lọ. Wọ́n lọ bi Ifá léèrè, Ifá si ṣe atọ́nà Ajẹbú wí pé kí ó lọ tẹ̀dó sí ibi kan, èyí tí à ń pè ní Imẹ̀pẹ̀. Olóde àti Àjànà darapọ̀ wọ́n tẹ ibi tí à ń pè ní Ìta Ajànà dó, èyí sì wà ni ìlú Ìjẹ̀bú-Òde títí di òní yìí.