Otan Ayegbaju: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Content deleted Content added
No edit summary
Ìlà 5:
 
== Ìtàn ==
[[File:Short oral history of Igbeti in igbeti dialectlanguage by a native speaker (non-subtitled).webm|thumb|Short oral history of Igbeti in igbeti dialect by a native speaker (non-subtitled)|250px]]
Ohun tí ìtàn àtẹnudẹ́nu fi yé wa ni wípé àwọn ọmọ [[Odùduwà]] tí wọ́n rin ìrìn-àjò wá sí Ọ̀tan ní ǹkan bí ọgọ́rùn ún márùn ún ọdún sẹ́yìn láti [[Ilé-Ifẹ̀ ]] ni wọ́n tẹ̀dó sí Ọ̀tan-Ilé ṣáájú kí wọ́n tó lọ sí Ọ̀tan Kòtò tí ó di Ọ̀tan Ayégbajú lónì-ín. Ọ̀tan jẹ́ ìlú tí àṣà àti ìṣe [[Yorùbá]] ti fìdí múlẹ̀ púpọ̀, tí púpọ̀ nínú àwọn olùgbé ibẹ̀ yàtọ̀ sí àwọn ọmọ bíbí ibẹ̀ jẹ́ àwọn elédè [[Ìjẹ̀ṣà]] àti [[Ilú-ọba Ọ̀yọ́|Ọ̀yọ́.]]<ref name="villagespec.com 2018">{{cite web | title=History Of Otan-Ile | website=villagespec.com | date=2018-08-15 | url=https://villagespec.wordpress.com/2018/08/15/otanile/ | access-date=2021-07-21}}</ref>