Abeokuta Grammar School: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Content deleted Content added
k Àkójọpọ̀ àwọn àwòrán ti Ilé - Ẹ̀kọ́ Gírámà Abẹ́òkúta
Àwọn àlẹ̀mọ́: VisualEditor Àtúnṣe ojú fóónù Àtúnṣe ojú fóónù
No edit summary
Ìlà 174:
| picture_caption2 =
}}
Ilé - Ẹ̀kọ́ Abẹ́òkúta Girama jẹ́ ilé - ẹ̀kọ́ gíga ní ìlú Abẹ́òkúta, Ìpínlẹ̀ Ògún, Nàìjíríà. Agbègbè Ìdí - Aba ni Abẹ́òkúta ni ó wà báyìí. Wọ́n sábà máa ń pè é ní Ilé - Ẹ̀kọ́ Gírámà àkọ́kọ́ ní Nàìjíríà, gbogbo àwọn ọmọ orílẹ̀èdè láti apá Nàìjíríà, Iwọ̀-oòrùn Áfíríkà, Gúúsù - Ilẹ̀ Áfíríkà, Yúróòpù, àti ní Éṣíyà ni wọ́n lọ síbẹ̀
 
'''Ilé - Ẹ̀kọ́ Abẹ́òkúta Girama''' jẹ́ ilé - ẹ̀kọ́ gíga ní ìlú Abẹ́òkúta, Ìpínlẹ̀ Ògún, Nàìjíríà. Agbègbè Ìdí - Aba ni Abẹ́òkúta ni ó wà báyìí. Wọ́n sábà máa ń pè é ní Ilé - Ẹ̀kọ́ Gírámà àkọ́kọ́ ní Nàìjíríà, gbogbo àwọn ọmọ orílẹ̀èdè láti apá Nàìjíríà, Iwọ̀-oòrùn Áfíríkà, Gúúsù - Ilẹ̀ Áfíríkà, Yúróòpù, àti ní Éṣíyà ni wọ́n lọ síbẹ̀
== Àjọ Ṣọ́ọ̀sì Anglican Agbègbè Abẹ́òkúta ni wọ́n da ilé - ẹ̀kọ́ náà sílẹ̀ ní ọdún 1908. Àwọn èèyàn jàkànjàkàn ni wọ́n lọ sí ilé - ẹ̀kọ́ náà bẹ̀rẹ̀ láti orí àwọn òṣèlú Nàìjíríà àti iṣẹ́ - ọnà, bákan náà ni olùkọ́ àti olóṣèlú ajàfẹ́ẹ̀tọ́ Fúnmiláyọ̀ Ransome-Kútì àti ọmọ rẹ̀, olórin Fẹlà Aníkúlápó - Kutì. ==
 
== Ní ìlànà ìmọ̀-ẹ̀kọ́, àwọn akẹ́kọ̀ọ́ Ilé Ẹ̀kọ́ Gírámà Abẹ́òkúta lọ fún ìdánwò ní Royal College Preceptors ni 1909 tí wọ́n sì jókòó fún Ìdánwò Cambridge abẹ́lé ni 1911. Ó di ilé - ẹ̀kọ́ takọ-tabo ni 1914 nígbà tí wọ́n gba àwọn obìnrin. Ní 1939, ilé - ẹ̀kọ́ kó àwọn akẹ́kọ̀ọ́ lọ fún Ìdánwò Ilé-ẹ̀kọ́ Cambridge, ní ọdún 1996  ìjọba Nàìjíríà sún ipò rẹ̀ sókè sí Ilé - Ẹ̀kọ́ Aláwòkọ́ṣe. ==
 
== AGSOBA jẹ́ ẹgbẹ́ àwọn akẹ́kọ̀ọ́ àtijọ́ (ọkùnrin àti obìnrin) tí Ilé - Ẹ̀kọ́ Gírámà Abẹ́òkúta, òun sì ni ẹgbẹ́ akẹ́kọ̀ọ́ tí ó dàgbà jù ní Nàìjíríà. Aláṣẹ Ìgbìmọ̀ Gíga ló darí rẹ̀ tí olú - iléeṣẹ́ sì wà ní Abẹ́òkúta, ẹgbẹ́ náà ṣiṣẹ́ ni àwọn ẹ̀ká jákèjádò Nàìjíríà àti ní àgbáyé. ==
 
== Ẹgbẹ́ akẹ́kọ̀ọ́ mẹ́ta láti Ilé Ẹ̀kọ́ Gírámà Abẹ́òkúta ní Ìpínlẹ̀ Ògùn jáwé olúborí orílẹ̀èdè níbi ipele Ètò-amúùlúdùn àti Èrò - tuntun ní Ìdíje Diamond lásìkò Ayẹyẹ National Pitch Event ní ọdún 2019. Ó wáyé ní Àjọ ìdàgbàsókè ọ̀dọ́ tí ìyára-ìkàwé Ààrẹ Olúṣẹ́gun Ọbásanjọ́Ìtàn ==
Ile-eko naa ni ipilẹ ni ọdun 1908 nipasẹ Igbimọ Ijo Agbegbe ti Abeokuta (Anglicans).