Ọbáfẹ́mi Awólọ́wọ̀: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Content deleted Content added
Ẹ̀ka:Àwọn ọmọ Yorùbá (lower level category)
Ìlà 21:
 
== Ìgbà èwe ==
[[File:Obafemi Awolowo car.jpg|thumb|left|Ọkọ̀ ayọ́kẹ́lẹ́ Ọbáfẹ́mi Awólọ́wọ̀]]
A bí i ní [[6 March|ọjọ́ kẹfà oṣù kẹta]] ọdún 1909 ní [[Ìkẹ́nnẹ́]] tó wà ní [[Ipinle Ogun|ìpínlẹ̀ Ògùn]] lónìí. Ọmọ àgbẹ̀ tí ó fi iṣẹ́ àti oògùn ìṣẹ́ sọ ara rẹ̀ di ọ̀mọ̀wé, Awólọ́wọ̀ lọ ilé ẹ̀kọ́ Anglican àti Methodist ní Ìkẹ́nnẹ́ àti sí Baptist Boys' High School ní [[Abeokuta|Abẹ́òkúta]].<ref>''Nigerian Political Parties: Power in an Emergent African Nation'', R. L. Sklar (2004), Africa World Press, ISBN 1-59221-209-3</ref> Lẹ́yìn rẹ̀ ó lọ sí Wesley College ní [[Ibàdàn|Ìbàdàn]] tí ó fi ìgbà kan jẹ́ olú-ìlú [[Agbègbè Apáìwọ̀òrùn Nàìjíríà]] láti ba di Olùko. Ní ọdún 1934 , ó di olùtajà àti oníròyìn. Ó ṣe olùdarí àti alákòóso Ẹgbẹ́ Olùtajà Àwọn Ọmọ Nàìjíríà (Nigerian Produce Traders Association) àti akọ̀wé gbogbogbòò Ẹgbẹ́ Àwọn Awakọ̀ Ìgbẹ́rù Ọmọ Ilẹ̀ Nàìjíríà (Nigerian Motor Transport Union). <ref name =political>{{cite book|url=https://books.google.com.ng/books?id=ijfJhANmGG8C&q=Obafemi+Awolowo+Inner+temple&dq=Obafemi+Awolowo+Inner+temple&hl=en&sa=X&ei=Hc5eVYvQEoq17gaSxoKwCg&ved=0CCsQ6AEwBDgK|title=Political Leaders of Contemporary Africa South of the Sahara: A Biographical Dictionary|author=Harvey Glickman|publisher=Greenwood Press|year=1992|isbn=9780313267819}}</ref>