Emmanuel Ifeajuna: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Content deleted Content added
Mo se afikun imo oju ewe yi
kNo edit summary
Ìlà 9:
 
Ní idije ere idaraya ni ọdun 1954 ni Vancouver, o dije pẹlu bata ẹsẹ kan, ẹsẹ osi, sibẹsibẹ, o bori nipa fifo ifo iwon ẹsẹ bata mẹfa o le mẹjo (mita 2.03), eleyi ti o ta yọ ohun ti ẹnikẹni ti fo ri boya ni ti ere idije ni tabi ni ti orilẹ-ede Gẹẹsi. Ami ẹyẹ wura ti o gba nidi eyi jẹ igba akọkọ ti alawọ dudu yoo gba nibi idije to laami laaka lagbaye. Idije ifo fifo yii gbajugbaja ni odun naa fun awon alawọ dudu nitoripe Patrick Etolu ti o jẹ ọmọ orilẹ-ede Uganda naa se ipo keji tẹle Ifeajuna tí Osagie, ti o je ọmọ orilẹ-ede Naijiria si ṣe ipo kẹta. T'iIu t'ifọn ni wọn fi ki Ifeajuna kaabọ nigba ti o pada de ilu Eko, ijo ati ayọ ni wọn fi gbe yipo ilu Eko kí o to dari si ibi a wẹjẹ-wẹmu kan nibi ti o ti sọ̀rọ̀. Aworan rẹ̀ si di ohun ti a ya si ẹyin iwe ajakọ ti awọn ọmọ ile-iwe alakọbẹrẹ ati girama n lo ni orilẹ-ede Naijiria<ref name=":0" />.
 
== Ose ilu ati Ile Eko Giga ==
Leyin gbati Ifeajuna ti gba ami eye wura ,o pada si ile iwe giga ti ilu Ibadan lati kawe oye ti siayensi ni odun 1954.O para po mo awon omoti ile iwe giga to feran nkan ose ilu.Ni ile iwe giga ti [[:en:University_of_Ibadan|UniversityCollege]] Ibadan .
 
== Àwọn ìtọ́kasí ==