Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò "Clement Nyong Isong"

247 bytes added ,  10:41, 14 Oṣù Kẹ̀wá 2021
k
Kò sí ìsọníṣókí àtúnṣe
k
}}
}}
'''Clement Nyong Isong''', [[Order of the Federal Republic|CFR]] tí wọ́n bí ní ogúnjọ́ oṣù kẹrin ọdún 1920, ó sìn kú ní ọjọ́ kọkàndínlọ́gbọ̀n oṣù karùn-ún ọdún 2000 (20 April 1920 – 29 May 2000). O jẹ́ gbajúmọ̀ olóṣèlú àti onímọ̀ ilé-ìfowópamọ́ tí ó jẹ́ Gómìnà [[Ilé Ìfowópamọ́-àgbà tí Nàìjíríà]] lọ́dún 1967 sí 1975<ref name="Central Bank of Nigeria &#124; Home 2006">{{cite web | title=Events & Facts | website=Central Bank of Nigeria &#124; Home | date=2006-02-20 | url=https://www.cbn.gov.ng/HistoryFactsAll.asp?sign=1&NAV=14 | access-date=2021-10-14}}</ref> nígbà ìṣèjọba ológun Ọ̀gágun [[Yakubu Gowon]]. Wọ́n wá padà dìbò yàn án gẹ́gẹ́ bí gómìnà [[ìpínlẹ̀ Cross River]] lọ́dún 1979 sí 1983.<ref name=cbank>{{cite web |url=http://www.cenbank.org/Currency/Biodata/Isong.asp |title=Dr. Clement Isong |publisher=Central Bank of Nigeria |accessdate=2010-02-28}}</ref>
 
== ìgbé ayé rẹ̀ ==