Ola Rotimi: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Content deleted Content added
DEFAULTSORT
Ìlà 30:
 
=== Lẹyìn ọ̀pọ̀ Odún ===
Nígbàtí ó padá sí Nàìjíríà ní bíi 1960, ṣisẹ́ olùkọ́ ni Yunifàsíti Ifẹ̀ ti wọ́n ń pè ní Ọbáfẹ́mi Awólòwọ̀ Yunifásit̀ì nísìn, níbi tí ó tí dà ilé iṣẹ́ Olokun Acting Company<ref name="CambridgeGuide">"Rotimi, Ola", in Martin Banham, Errol Hill & George Woodyard (eds), ''The Cambridge Guide to African & Caribbean Theatre'', Cambridge University Press, 1994, p. 81.</ref> àti Port Harcourt sílẹ̀. Lápákan, nítoní ètò òṣèlú &nbsp; Nàìjíríà, Rotimi lo púpọ̀ nínu 1990s ẹ́ ní Caribbean àti United States, níbi ti ó ti kọ́ akẹkọ ní ilé ìwé Macalester College ní St. Paul, ní Minnesota. Ni odún 2000, ó padà sí Ilè Ifẹ̀, ó darapọ̀ ẹ̀ka èkọ́ Ọbáfẹ́mi Awólòwọ̀ Yunifásit̀ì níbí tí ó tí ṣisẹ́ olùkọ́ tí ó fi kú. Hazel (ìyàwó rẹ́) kú ní Oṣù karun odún 2000, oṣù díẹ sí ìgbà tí Rotimi kú.
 
Àwọn eré tí ó ṣe ní ''The Gods Are Not to Blame'' (gbejade 1968; tẹ̀jade 1971), àtúnsọ ''Sophocles Oedipus the King''<ref name="CambridgeGuide" />, ''Kurunmi and the Prodigal'' (gbejade 1969; tẹ̀jade bíi Kurunmi, 1971), tí ó kọ fún Ife Festival of Arts; ''Ovonramwen'' ''Nogbaisi'' (gbejade 1971;tẹ̀jade 1974), nípa Oba Benin empire; àti ''Holding Talks'' (1979).
 
Lẹ́yìn ìgbà náà, wọ́n ṣe àfihàn àwọn eré :''A Tragedy of the Ruled'' (1983) àti ''Hopes of the Living Dead'' (1988), tó ṣe ní University of Port Harcourt, ó jẹ́ eré tó gbòpò ní ẹ̀ka tíátà OAU. Radio play ''Everyone His/Her Own Problem ''diàtẹjade ní odún 1987''. ''Ìwé rẹ̀, '' African Dramatic Literature: To Be or to Become? ''di titejade ní odún 1991
Jẹ́ kíkójáde láti "https://yo.wikipedia.org/wiki/Ola_Rotimi"