Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò "Ola Rotimi"

51 bytes removed ,  09:13, 25 Oṣù Kẹ̀wá 2021
k
Kò sí ìsọníṣókí àtúnṣe
k
}}
 
'''Olawale Gladstone Emmanuel Rotimi''', tí a mọ̀ sí '''Ola Rotimi''' (13 Oṣù kẹrin 1938 – 18 Oṣù &nbsp; kẹjọ &nbsp; 2000),<ref>"Ola Rotimi", in Hans M. Zell, Carol Bundy, Virginia Coulon, ''A New Reader's Guide to African Literature'', Heinemann Educational Books, 1983, p. 474.</ref> jẹ́ ògbóńta &nbsp; olùkọ̀tàn, ọmọ orìlé èdè Nàìjírìà àti olùdarí tíátà . Wọn a má pèé ní "Okùnrin oní tíátà tí kò lábàwọń –òṣèré, olùdarí , onijo kòríógíráfì, àti oníṣẹ́-ọnà – tí ó ṣe àyè iṣẹ́, tí ọnà &nbsp; kópa ní ìgbésí ayé rẹ̀".<ref>[http://www.guardian.co.uk/news/2000/oct/17/guardianobituaries1 Martin Banham, Obituary: "Ola Rotimi – Playwright who put Nigeria's dramas on the stage",] ''The Guardian'', 17 October 2000.</ref>
 
== Ìgbésíayé ==
 
=== Ìgbà èwe ===
Rotimi jẹ́ ọmọ Samuel Gladstone Enitan Rotimi, ọmọ yorùbá ẹlẹ́rọ tí àwọn òyìnbó ń pè ní "steam-launch engineer" (ó jẹ́ olùdarí àti alagbéjáde àwọn òṣèré tí kò tí ì dí ògbóntà) àti Dorcas Adolae Oruene Addo, ọmọ Ijaw tí ó fẹ́ran eré ìtàgé. Wọ́n bíi sí ìlú Sapele ní Nàìjíría; Onírúúru àṣà ni àkòrí iṣẹ́ rẹ̀. Ó lọ sí ilé ìwé Cyprian ni ìlú Port Harcourt láti ọdún 1945 sí 1949, ilé ìwé St Jude láti ọdún 1951 sí 1952 àti ilé ìwé Methodist Boys High School ní ilú Èkó, kí ó tó rìriǹàjò lọ sí United States ni ọdún 1959 lati kọ́ ẹ̀kọ́ ni Boston University, níbi tí ó ti gba oyè àkọ́kọ́ ní áàtì (B A). Ní ọdún 1965, ó fẹ́ aràbìrin Hazel Mae Guadreau, tí ó kọ́kọ́ wá lati Gloucester; Hazel kàwé ní Boston University, níbi tí ó ti kọ́ ẹ̀kó ijó, ohún àti orin. Ní ọdún 1966, Olá gba oyè kejì (MA) lati ilé ìwé Yale School of Drama,<ref group="nb" name="M.A." /> níbi tí ó tí olùkọ́ eré kíkọ eré lítíréṣò.<ref group="nb" name="project-play" />
<span class="cx-segment" data-segmentid="83"></span>
 
=== Iṣẹ́  tíátà ===
Rotimi ma ń ṣàyẹ̀wò ìtàn Nàíjíríà àti àṣ̀à nínú irẹ́ rẹ̀. Wọn ṣe àfifàn eré rẹ̀ àkọ́kọ́, ''To Stir the God of Iron'' (gbejade ní &nbsp; 1963) àti ''Our Husband Has Gone Mad Again'' (gbejade ní 1966; tẹjade ní 1977) ní ilé ẹ̀kọ́ orí ìtàgé ti Boston University àti Yale University.
 
<span class="cx-segment" data-segmentid="93"></span>