Ola Rotimi: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Content deleted Content added
k +word
Ìlà 20:
== Ìgbésíayé ==
 
=== Ìgbà èwe rẹ̀===
Rotimi jẹ́ ọmọ Samuel Gladstone Enitan Rotimi, ọmọ yorùbá ẹlẹ́rọ tí àwọn òyìnbó ń pè ní "steam-launch engineer" (ó jẹ́ olùdarí àti alagbéjáde àwọn òṣèré tí kò tí ì dí ògbóntà) àti Dorcas Adolae Oruene Addo, ọmọ Ijaw tí ó fẹ́ran eré ìtàgé. Wọ́n bíi sí ìlú Sapele ní Nàìjíría; Onírúúru àṣà ni àkòrí iṣẹ́ rẹ̀. Ó lọ sí ilé ìwé Cyprian ni ìlú Port Harcourt láti ọdún 1945 sí 1949, ilé ìwé St Jude láti ọdún 1951 sí 1952 àti ilé ìwé Methodist Boys High School ní ilú Èkó, kí ó tó rìriǹàjò lọ sí United States ni ọdún 1959 lati kọ́ ẹ̀kọ́ ni Boston University, níbi tí ó ti gba oyè àkọ́kọ́ ní áàtì (B A). Ní ọdún 1965, ó fẹ́ aràbìrin Hazel Mae Guadreau, tí ó kọ́kọ́ wá lati Gloucester; Hazel kàwé ní Boston University, níbi tí ó ti kọ́ ẹ̀kó ijó, ohún àti orin. Ní ọdún 1966, Olá gba oyè kejì (MA) lati ilé ìwé Yale School of Drama,níbi tí ó tí olùkọ́ eré kíkọ eré lítíréṣò.
<span class="cx-segment" data-segmentid="83"></span>
Jẹ́ kíkójáde láti "https://yo.wikipedia.org/wiki/Ola_Rotimi"