Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò "Wikipedia:Abẹ́ igi"

949 bytes added ,  18:06, 7 Oṣù Kọkànlá 2021
k
 
:Congratulations to the elected and selected members of the drafting committee, they are all welcome on board. [[Oníṣe:Agbalagba|Agbalagba]] ([[Ọ̀rọ̀ oníṣe:Agbalagba|ọ̀rọ̀]]) 10:59, 3 Oṣù Kọkànlá 2021 (UTC)
 
==Ìjábọ̀ Ẹgbẹ́ Yorùbá Wikimedians User Group fún ọdún 2021-2022==
Ẹgbẹ́ Yorùbá Wikimedians User Group ń fi akókò yí kéde rẹ̀ fún gbogbo ọmọ ẹgbẹ́ ati àwọn aláfikún sí ọpọ́n ìmọ̀-ọ̀fẹ́ Yorùbá Wikipedia wípé èsì tabí àbọ̀ àwọn iṣẹ́ àkànṣe ọlọ́kan-ò-jọ̀kan tí a ti gbé ṣe láàrín ọdún 2021 ti wà ní akọsílẹ̀ báyí fún àgbéyẹwò yín, kí ẹ sì lè mọ bí ẹgbẹ́ náà ti ń sapá láti mú ìdàgbà-sókè bá ìmọ̀-ọ̀fẹ́ Wikipedia èdè Yorùbá àti gbogbo ọmọ ẹgbẹ́ aláfikún Yorùbá Wikipedia lápapọ̀ ṣe ń kópa ribi ribi sí.
Ẹ lè ìtàkùn ìsàlẹ̀ yí láti kà nípa rẹ̀.
https://meta.wikimedia.org/wiki/Yoruba_Wikimedians_User_Group/2021_Report
Ẹ ṣeun [[Oníṣe:Agbalagba|Agbalagba]] ([[Ọ̀rọ̀ oníṣe:Agbalagba|ọ̀rọ̀]]) 18:06, 7 Oṣù Kọkànlá 2021 (UTC)