Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò "Adegoke Adelabu"

3,615 bytes added ,  17:39, 9 Oṣù Kọkànlá 2021
==Ibẹ̀rẹ̀ ayé rẹ̀==
Adélabú tí a bí sínú ẹbí ọ̀gbẹ́ni Sanusi Aṣiyanbí ati abilékọ Awujola Adélabú.{{sfn|Post|Jenkins|1973|p=33}} ní ọdún 1915. Ìyá Adélabú ni ó jẹ́ ìyàwó kejì nílé ọmọ rẹ̀ tí ó sì ṣílẹ̀ wọ̀ lẹ́yìn ìgbà diẹ̀ tí ó bí Adégòkè tan, èyí ni ó mú kí ẹ̀gbọ́n Ìyá rẹ̀ ó gbà á tọ́. Ó lọ sí ilé-ẹ̀kọ́ alàkalẹ̀ọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀ ti [[Church Mission Society|C.M.S.]] ní Kúdẹtì nígboro ìlú Ìbàdàn láàrín ọdún 1925-1929, tí ó sì kàwé gba ''Standard IV àti V'' ní C.M.S. Central school, Mapo. Lóòtọ́ Musulumi ni oun àti ẹbí rẹ̀, amọ́ ọ̀dọ̀ Àbúrò bàbá rẹ̀ tí ó gbé lọ́dọ̀ rẹ̀ mu lọ sí ilé-ẹ̀kọ́ tí ó jẹ́ ilé-ẹ̀kọ́ ẹlẹ́sì Kìrìstẹ́nì ní ìlú [[Ìbàdàn]], tí ó sì gba ìwé-ẹ̀rí ilé-ẹ̀kó náà tí fi lè wọ ilé-ẹ̀kọ́ CMS. Ó lọ sí ilé-ẹ̀kọ́ Government College ti ìlú [[Ìbàdàn]] láàrín ọdún {{sfn|Post|Jenkins|1973|p=36}} 1931 sí ọdún 1936 gẹ́gẹ́ bí aṣojú akẹ́kọ̀ọ́ inú ọgbà. Ní ọdún 1936, Adélabú wọ ilé-ẹ̀kọ́ [[Yaba Higher College]], lẹ́yìn èyí, ó rí ètò ẹ̀kọ́ ọ̀fẹ́ gbà lọ́wọ́ ilé-iṣẹ́ [[United Africa Company|UAC]] láti kẹ́kọ̀ọ́ nípa imọ̀ okòwò.{{sfn|Post|Jenkins|1973|p=37}} Láìpẹ́, Adélabú kúrò nílé ẹ̀kọ́ lẹ́yìn oṣù mẹ́fà tí wọ́n fun ní ẹ̀kọ́ ọ̀fẹ́. Ọkàn nínú àwọn akọ́ṣẹ́-mọṣẹ́ tí ó ti mọ̀ ri ní ilé-iṣẹ́ [[kòkó]] tí ó tún jẹ́ ọ̀gá àgbà ní ilé-iṣẹ́ UAC fun ní iṣẹ́ gẹ́gẹ́ bí amúgbá-lẹ́gbẹ̀ẹ́ adarí àgbà ilé-iṣẹ́ wọn ní ìlú Ìbàdàn . Lẹ́yìn tí ó de ibẹ̀, Adélabú gbé ìgbésẹ̀ bí ilé-iṣẹ́ ṣe lè máa to kókó lọ́nà ará ọ̀tọ̀, ìgbésẹ̀ yí sì ni ó jẹ́ kí ó ri ìgbéga sípò igbákejì adarí lẹ́ka ìtajà. Adélabú kúrò ní ilé-iṣẹ́ UAC ní ọdún 1937 láti dara pọ̀ mọ́ iṣẹ́ owó kòkó títà fúnra rẹ̀, láìpẹ́, ó di lààmì-laaka nínú iṣẹ́ òwò kòkó rẹ̀. Lẹ́yìn tí ó di gbajúmọ̀ níbi iṣẹ́ rẹ̀ tán ni ó bẹ̀rẹ̀ ní ń wá iṣẹ́ ìjọba. {{sfn|Post|Jenkins|1973|p=46}} Ó di olùbẹ̀wò agbà fún ohun ọ̀gbìn ní ọsún 1939. Ó ṣiṣẹ́ pẹ̀lú ilé-iṣẹ́ UAC títí di ọdún 1945, Adélabú sì kúrò ní ilé-iṣẹ́ náà nígbà tí Richardson kúrò ní ilé-iṣẹ́ UAC. {{sfn|Post|Jenkins|1973|p=51}}. Lẹ́yìn èyí, Adélabú pa gbogbo [[owó]] tí ó ti rí kó jọ ní ó papọ̀ tí ó fi da òwò òwú sílẹ̀ pẹ̀lú ''Levantine'' ní ilẹ̀ Ìbàdàn.
 
===Ipa rẹ̀ nínú ìṣèlú===
==Ọdún 1949–1953==
Adélabú bẹ̀rẹ̀ ìṣèlú nígbà tí ó ṣe ìkúnlápá fún akitiyan àwọn olóyè ati àwọn Mọ́gàjí ẹgbẹ́ rẹ̀ tako [[Salami Agbájé]]. Àwọn ènìyàn gbàgbọ́ wípé orí Adélabú pé púpọ̀, ó sì kàwé, òun gan ni ó yẹ nípò tí Salami Agbájé wà. Àwọn olóyè ati awọn Mọ́gají wọ̀nyí nílò ẹni tí ó lè bá wọn kọ̀wé ati àríwísí láti lè fẹsẹ̀ ẹ̀hónú wọn múlẹ̀, wọ́n tọ Adélabú lọ fún ìrànlọ́wọ́. Adélabú gbà láti ràn wọ́n lọ́wọ́ pẹ̀lú àdéhùn wípé wọn yóò fun ní ipò akọ̀wé wọn. Salami Agbájé ni ó jẹ́ oníṣòwò tí ó dipò Ọ̀tún Balógun Ilẹ̀ [[Ìbàdàn]] mú, òun sì ni ẹnì kẹ́ta tí ipò Ọba Olúbàdàn kàn. Ó kàwé, ó lówó, ó sì gbajúmọ̀ pẹ̀lú,àmọ́ púpọ̀ nínú àwọn olóyè wọ̀nyí ni wọn kò fẹ́ràn rẹ̀ látàrí wípé wọn kò lè wojú rẹ̀. Àwọn olóyè kékèké ati àwọn Mọ́gàjí bẹ̀rẹ̀ sí polongo takòó kí wọ́n lè yọ ọ́ nípò kí ó má ba di [[Olubadan]]. Adélabú ni ó ń ṣe agbátẹrù fún àwọn akọsílẹ̀ ati ìwé ìtakoni tí wọ́n fi ń ṣọwọ́ sí àwọn òyìnbó amúnisìn tí wọ́n ṣe ìjọba nígbà máà nípa Salami Agbájé. Lásìkò yí, wọ́n yan Adélabú sí ipò akọ̀wé Ẹgbẹ́ Ọmọ Ìbílẹ̀, gẹ́gẹ́ bí ẹgbẹ́ ìbílẹ̀ tí ó tako Agbaje, tí Bello Asasi tí ó jẹ́ ọ̀kan lára ọmọ Alẹ́ṣinlọ́yẹ́ Olúbàdan àná .{{sfn|Sklar|p=291}} Nígbà tí òrọ̀ yí d'étí ìgbọ̀ awọn òyìnbó amúnisìn, wọ́n gba Agbájé níyànjú kí ó yẹ̀bà fún kíkópa nínú ẹgbẹ́ ìbílẹ̀ awọn ọ̀yínbó yí lo ànfaní yí láti ṣe atúntò sí ẹkùn Ilẹ̀ Ìbàdàn nípa yíyọ ẹkùn Ọ̀ṣun kúrò lára Ìbàdàn. Ìgbésẹ̀ awọn ìjọba àmúnisìn yí kò tẹ́ àwọn ènìyàn ati ẹlẹ́gbẹ́jẹgbẹ́ ilẹ̀ Ìbàdàn lọ́rùn , wọ́n sì kóra jọ nílanà ti ìṣèlú láti dáàbò bo ẹkùn Ìbàdàn.
 
During the local elections in 1951, Adelabu's Egbe Omo Ibile, [[Augustus Akinloye]], and a youth group from Ibadan Progressive Union formed the Ibadan People's Party as a challenge to the old guards of the Ibadan Progressive Union. Adelabu capitalized on some anti-[[Ijebu people|Ijebu]] sentiments among native Ibadan residents especially after the loss of Oshun division which was supported by [[Action Group (Nigeria)|Action Group]] leaders such as [[Awolowo]], an Ijebu-man and [[Akintola]]. The new party won all six seats to the Western Regional Assembly. However, an informal alliance proposed by Adelabu to support [[National Council of Nigeria and the Cameroons|NCNC]] fell apart and four of the elected members joined AG. Adelabu then became more active in the organization of NCNC in Ibadan and became the secretary of the party's Western Province Working Committee while earning recognition within the party as the only IPP legislator who stayed with NCNC. Soon his profile began to rise nationally that in 1952, he published a book, Africa in Ebullition about his political thoughts. To provide a formidable organization to challenge AG in the 1954 elections, Adelabu formed a new organization, the Ibadan Taxpayers Association which was an attempt to attract mass following based on tax reform. The group then formed an alliance with some a farmers group called Maiyegun to become Mabolaje Grand Alliance.
 
 
 
 
=== Ọdún 1954–1958===