Olu Falae: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Content deleted Content added
kNo edit summary
Àwọn àlẹ̀mọ́: VisualEditor Àtúnṣe ojú fóónù Àtúnṣe ojú fóónù Advanced mobile edit
k Mo ṣe àfikún
Àwọn àlẹ̀mọ́: VisualEditor Àtúnṣe ojú fóónù Àtúnṣe ojú fóónù Advanced mobile edit
Ìlà 28:
Ó fi ipò akọ̀wé ìjọba silẹ láti ṣe mínísítà ètò owóńná ìjọba àpapọ̀ ní ọdún 1990 ní àsìkò ìjọba ológun Ibrahim Babaginda. Wọ́n yọ ọ́ ní iṣẹ́ ní Oṣù Ògún ọdún 1990. Lẹ́hìn náà, ó darapọ̀ mọ́ ètò ìyípadà ìjọba àwarawa.
 
[11/10, 13:44] Omosalewa Ajoke: Iṣẹ́ ìjọba. Nígbà tí ó parí ẹ̀kọ́ dìgírì nínú ètò ọ̀rọ̀ ajé Falae darapọ̀ mọ́ àwọn òṣìṣẹ́ ìjọba gẹ́gẹ́ bí igbákejì akọ̀wé, Ẹgbẹ́ àwọn àpapọ̀ áwọn òṣìṣẹ́ Orílẹ̀èdè. Ó padà di olùrànlọ́wọ́ akọ̀wé àgbà. Ní ọdún 1971, wọ́n gbé lọ sí Iléeṣé ìṣètò gbòógì (Central Planning Office). Lásìkò rẹ̀ ní iléeṣẹ́ yìí, ẹ̀ka yìí kópa nínú ìgbékalẹ̀ Ètò ìdàgbàsókè fún Orílẹ̀èdè ìkẹta (Third National Development Plan) àti
 
 
Jẹ́ kíkójáde láti "https://yo.wikipedia.org/wiki/Olu_Falae"