Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò "Olu Falae"

25 bytes removed ,  08:09, 11 Oṣù Kọkànlá 2021
k
Kò sí ìsọníṣókí àtúnṣe
k
 
 
==Ìgbé àyè Ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ àti Ètòètò ẹ̀kọ́ Èkọ́rẹ̀==
 
Wọ́n bí Falae sínú ìdílé Olóyè  Joshua Alekete àti Abigail Aina Falae ní  ọjọ́ kọkànlélógún oṣù Ọ̀wàrà, ọdún 1938 ní ìlú Abo, Àkúrẹ́. Ọmọ ìlú Òǹdó ni Joshua Falae ṣùgbọ́n torí àwọn àǹfààní tó wà nínú àgbẹ̀ kókó, ẹbí Falae àti díẹ̀ lára àwọn ọmọ Àkúrẹ́ kó lọ sí ìletò kan tó súnmọ́ tí wọ́n pé ní Ago-Abo tí a tún mọ̀ sí Ìlú Abo níbi tí wọ́n tẹ̀dó sí bíi olùdásílẹ̀. Wọ́n padà fi Bàbá Falae jẹ olóyè abúlé Ago - Abo. Ìlú Ìgbàrà-Òkè ni wọ́n tí bí àti tọ́ Ìyá Falae ó sì kú lásìkò tó ń bímọ ní ọdún 1946 nígbà tí Falae jẹ́ ọmọ ọdún mẹ́jọ péré. Bàbá àti Ìyá Bàbá ré ni wọ́n tọ dàgbà. Ìyá bàbá rẹ̀ ni (Olóyè Ọ̀sanyìntuke Falae - (ọmọ Adedipe) tí ó jẹ ọmọọmọ iya Déjì tí Àkúrẹ́ àti ọmọ Elemo ti Àkúrẹ́, Olóye Adedipe Oporua Atosin (Òun fúnra rẹ̀ ọmọọmọ Déjì Arakale ti Àkúrẹ́, Bàbá Òṣùpá). Falae lọ sí ilé - ẹ̀kọ́ alákọ̀bẹ́ẹ̀rẹ̀ Anglican ní ìlú Àkúrẹ́ níbi tí ó pàdé ìyàwó rẹ̀ tí ó fẹ́ Rachel Òlátúnbọ̀sún Fáshọ̀rántí, àbúrò olórí Afẹ́nifẹ́re Reuben Fáṣhọ̀rántí. Lẹ́yìn tí ó parí ẹ̀kọ́ àkọ́bẹ̀rẹ̀, ó ṣe ìdánwò láti wọlé sí Kọ́lẹ́jì Igbóbì, wọ́n sì gbà á wọlé ní ọdún 1953. Nígbà tí ó kẹ́kọ̀ọ́ gboyè ni Igbóbì, ó lọ parí ẹ̀kọ́ rẹ̀ ni Kọ́lẹ́jì Ìjọba, Ìbàdàn n
 
Ó fi ipò akọ̀wé ìjọba silẹ láti ṣe mínísítà ètò owóńná ìjọba àpapọ̀ ní ọdún 1990 ní àsìkò ìjọba ológun Ibrahim Babaginda. Wọ́n yọ ọ́ ní iṣẹ́ ní Oṣù Ògún ọdún 1990. Lẹ́hìn náà, ó darapọ̀ mọ́ ètò ìyípadà ìjọba àwarawa.
 
 
ti