Teodoro Obiang Nguema Mbasogo: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Content deleted Content added
No edit summary
No edit summary
Àwọn àlẹ̀mọ́: Àtúnṣe ojú fóónù Àtúnṣe ojú fóónù
 
Ìlà 24:
}}
 
'''Teodoro Obiang Nguema Mbasogo''' ({{IPA-es|te.o.ˈðo.ɾo o.ˈβjãŋɡ ˈŋ.ɡe.ma m.ˈba.so.go}}; ọjọ́ìbí 5 June 1942) ni olóṣèlú ará [[Equatorial Guinea|Guinea Ibialágedeméjì]] tó ti jẹ́ [[President of Equatorial Guinea|Ààrẹ ilẹ̀ Gínì Ibialágedeméjì]] láti ọdún 1979. Ó fi ipá gba ìjọba lọ́wọ́ arákùnrin bàbá rẹ̀, [[Francisco Macías Nguema]], nínú [[1979 Equatorial Guinea coup d'état|ìfipágbàjọba ológun osù kẹjọ ọdún 1979]], ó sì ti jẹ́ ààrẹ ibẹ̀ láoti ìgbà náà. Obiang dúró bíi [[Chairperson of the African Union|Alága]] ẹgbẹ́ [[African Union|Ìṣọ̀kan Áfríkà]] láti 31 January 2011 dé 29 January 2012. Òhun ni [[List of current longest-ruling non-royal national leaders|ẹnìkejì tó jẹ́ olórí orílẹ̀-èdè tó pẹ́ jùlọ ní orí àga tí kìí ṣe ọba]] ní àgbáyé.<ref>{{cite news|title=Equatorial Guinea: Palace in the jungle: Ordinary folk see none of their country's riches|url=https://www.economist.com/news/middle-east-and-africa/21694543-ordinary-folk-see-none-their-countrys-riches-palace-jungle|accessdate=12 March 2016|work=[[The Economist]]|date=12 March 2016}}</ref> Ni Oṣu kọkanla ọdun 2021, Teodoro Obiang Nguema Mbasogo ni a yan ni apejọ apejọ ẹgbẹ rẹ gẹgẹbi oludije fun saa kẹfa ninu idibo 2023.
 
{{ẹ̀kúnrẹ́rẹ́}}
 
==Itokasi==
{{reflist}}