Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò "Ṣàngó"

139 bytes removed ,  14:20, 24 Oṣù Kọkànlá 2021
k
Kò sí ìsọníṣókí àtúnṣe
k
k
 
'''Ṣàngó''' Olukoso, Oko Oya.
 
Òrìṣà Ṣàngó Jejẹ́ Okanọ̀kan larapàtàkì Awonlára Orisaàwọn tiòrìṣà awon yorùbáàwọn n[[Yorùbá]] bọ̀ń wọ́a ni àjànàkú kọjá a morí nǹkan fìrí, bí a bá rí erin, káwípe a rí erin ní òrọ̀ Ṣàngó jẹ́ láàárin àwon òrìsà ileẹ Yorùbábọ. Ṣàngó jẹ́ òrìsà takuntakun kan gbòógì láàárín àwon òrìsà tókù ní ilèeilẹ̀ Yorùbá. Ó jẹ́ orisà tí ìran rẹ̀ kún fún ìbẹ̀rù., Ìrísí, ìṣe àti ìsọ̀rọ̀ rẹ̀ pàápàá kún fún ìbẹ̀rù nígbàtí ó wà laayeláyé nítorípé ènìyàn la gbọ́ pé Ṣàngó jẹ́ tẹ́lẹ̀ kí ó tó di òrìṣà àráàkúnlẹ̀bọ. Ìtàn sọ wí pé ọmọ [[Ọ̀rányàn]] ni ṣàngó iń ṣe àti pé [[Ọya]], [[Ọ̀ṣun]] atiàti [[Ọbà]] jẹ́ni wọ́njẹ́ ìyàwó rẹ̀.
 
Ìhùwàsí búburú ati dídá wàhalá ati ìkọlura pẹ̀lú ìjayé fàmílétè-kí-n-tutọ́ pọ̀ lọ́wọ́ ṣàngó g̣ẹ́gẹ́ bí Ọba tó bẹ́ẹ̀ títí ó fi di ọ̀tẹ́yímiká, èyí jásí wí pé tọmọdé tàgbà dìtẹ̀ mọ́ ọ. Wọ́n fi ayé ni í lára. Ó sì fi ìlú Ọ̀yọ́ sílẹ̀ nígbẹ̀yìn-gbẹ́yín. Ó pokùnso sí ìdí igi àyàn kan lẹ́bà ọ̀nà nítòsí Ọ̀yọ́ nígbàtí Ọya: Ìyàwó rẹ̀ kan tókù náà sì di odò.
 
Ọgbọ́n tí àwọn ènìyàn ṣàngó tókù dá láti fi bá àwọn ọ̀tá rẹ̀ jà nípa títi iná bọlé wọn àti bẹ́ẹ̀bẹ́ẹ̀ lọ ni ó sọ ṣàngó di òrìṣà tí wọ́n ń bọ títí dòní tí wọ́n sì ńfi ẹnu wọn túúbá wí pé ṣàngó kò so: Ọba koso.
 
ÀWỌN ORÚKỌ TÍ ṢÀNGÓ Ń JẸ́
 
==Àwọn orúkọ tí Ṣàngó ń jẹ́==
Oríṣiríṣi orúkọ ni a mọ ṣàngó sí nínú èyí tí gbogbo wọn sì ní ìtumọ̀ tàbí ìdí kan pàtó ti a fi ńpè wọ́n bẹ́ẹ̀. Àwọn orúkọ bíi ìwọ̀nyìí:
 
1. #Olúkòso: Ẹnití a mọ̀ mọ́ kòso tàbí ọba tí ó wọlẹ̀ sí kòso.
2. #Arẹ̀kújayé:
 
3. #Àjàlájí:
2. Arẹ̀kújayé:
4. #Ayílègbe Ọ̀run:
 
5. #Olójú Orógbó: nítorípé orógbó ni obì tirẹ̀, òun ni ó sì máa ń ṣàfẹ́ẹ́rí nígbà ayé rẹ̀. Orógbó náà sì ni a máa ń lo ní ojúbọ ṣàngó títí di òní.
3. Àjàlájí:
6. #Èbìtì-àlàpà-peku-tiyẹ̀tiyẹ̀: Òrìṣà tí ó máa ń fi ìbínú gbígbóná pa ènìyàn ni àpalàyà tàbí àpafòn.
 
7. #Onibon ọ̀run: gẹ́gẹ́ bí òrìṣà ó ń mú kí àrá sán wá láti ojú ọ̀run pẹ̀lú ìrọ́kẹ̀kẹ̀ tó lágbára.
4. Ayílègbe Ọ̀run:
8. #Jàkúta: gẹ́gẹ́ bí òrìṣà tí ń fi òkúta jà (ẹdùn àrá). Irúfẹ́ òkúta kékẹrẹ́ kan tí ó máa sekúpa ènìyàn nípasẹ̀ ṣàngó
 
9. #Abọtumọ-bí-owú: Òrìsà léè wọlé pa ènìyàn bi ẹni pé ẹrù ń lá ni ó wólu irú ẹni bẹ́ẹ̀.
5. Olójú Orógbó: nítorípé orógbó ni obì tirẹ̀, òun ni ó sì máa ń ṣàfẹ́ẹ́rí nígbà ayé rẹ̀. Orógbó náà sì ni a máa ń lo ní ojúbọ ṣàngó títí di òní.
10. #Èbìtì-káwó-pònyìn-soro: Irúfẹ́ Òrìṣà tí ó jẹ́ wí pé ìṣọwọ́-sekúpa asebi rẹ̀ máa ńya ènìyàn lẹ́nu gidigidi.
 
11. #Alágbára-inú-afẹ́fẹ́: Òrìsà tí ó jẹ́ wípé ọwọ́jà a rẹ, máa ńwá láti inú afẹ́fẹ́ tàbí òfurufú ni.
6. Èbìtì-àlàpà-peku-tiyẹ̀tiyẹ̀: Òrìṣà tí ó máa ń fi ìbínú gbígbóná pa ènìyàn ni àpalàyà tàbí àpafòn.
12. #Abánjà-májẹ̀bi: òrìṣà tíí jà láì ṣègbè lẹ́yìn aṣebi tàbí ṣe àṣìmú elòmíràn fún oníṣẹ́ ibi.
 
13. #Lánníkú-ọkọ-ọya: Òrìsà tí o ni ẹ̀rù iku níkàwọ́.
7. Onibon ọ̀run: gẹ́gẹ́ bí òrìṣà ó ń mú kí àrá sán wá láti ojú ọ̀run pẹ̀lú ìrọ́kẹ̀kẹ̀ tó lágbára.
14. #Òkokoǹkò ẹ̀bìtì: Òrìsà tí ó le subú lu ènìyàn bii ìgànnán tí ó ti dẹnukọlẹ̀.
 
15. #Eléèmọ̀: Òrìsà tí ó ni èèmọ̀.
8. Jàkúta: gẹ́gẹ́ bí òrìṣà tí ń fi òkúta jà (ẹdùn àrá). Irúfẹ́ òkúta kékẹrẹ́ kan tí ó máa sekúpa ènìyàn nípasẹ̀ ṣàngó
 
9. Abọtumọ-bí-owú: Òrìsà léè wọlé pa ènìyàn bi ẹni pé ẹrù ń lá ni ó wólu irú ẹni bẹ́ẹ̀.
 
10. Èbìtì-káwó-pònyìn-soro: Irúfẹ́ Òrìṣà tí ó jẹ́ wí pé ìṣọwọ́-sekúpa asebi rẹ̀ máa ńya ènìyàn lẹ́nu gidigidi.
 
11. Alágbára-inú-afẹ́fẹ́: Òrìsà tí ó jẹ́ wípé ọwọ́jà a rẹ, máa ńwá láti inú afẹ́fẹ́ tàbí òfurufú ni.
 
12. Abánjà-májẹ̀bi: òrìṣà tíí jà láì ṣègbè lẹ́yìn aṣebi tàbí ṣe àṣìmú elòmíràn fún oníṣẹ́ ibi.
 
13. Lánníkú-ọkọ-ọya: Òrìsà tí o ni ẹ̀rù iku níkàwọ́.
 
14. Òkokoǹkò ẹ̀bìtì: Òrìsà tí ó le subú lu ènìyàn bii ìgànnán tí ó ti dẹnukọlẹ̀.
 
15. Eléèmọ̀: Òrìsà tí ó ni èèmọ̀.
 
== Àwọn Ìtọ́kasí ==