Ọyẹ́: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Content deleted Content added
New Page
Àwọn àlẹ̀mọ́: Àtúnṣe ojú fóónù Àtúnṣe ojú fóónù Advanced mobile edit
(Kò ní yàtọ̀)

Àtúnyẹ̀wò ní 11:02, 4 Oṣù Kejìlá 2021

Àdàkọ:Weather Ọyẹ́ àsìkò kan lápá iwọ̀ oòrùn Áfíríkà tí ó má a ń wáyé láàárín ìparí oṣù kọkànlá sí àárín oṣù kẹta ọdún. Ó jẹ́ àsìkò ẹrùn tàbí ọ̀gbẹlẹ̀ tí ó má a ń fa eruku.[1] The name is related to the word haramata in the Twi language.[2] Ó má a ń jẹ́ àsìkò òtútù, ní àwọn àgbègbè mìíràn ẹ̀wẹ̀, ó má ń jẹ àsìkò oru, èyí máa ń dá lórí àwọn ìṣẹ̀lẹ̀ ojú ọjọ́ ní irú àgbègbè bẹ́ẹ̀.[3]

Harmattan haze surrounding Abuja National Mosque in Abuja

Afẹ́fẹ́ Ọyẹ́ máa ń fẹ́ lásìkò ẹrùn tàbí ọ̀gbẹlẹ̀, ní àsìkò tó oòrùn kì í fi bẹ́ẹ̀ ràn dáradára.

Àwọn Ìtọ́kasí

  1. "Harmattan". Encyclopædia Britannica. Retrieved 22 July 2015. 
  2. Àdàkọ:Cite dictionary
  3. Geographical Review (1919): "Knox writes of this wind : The Harmattan is experienced as a wind which blows, especially in the months of December, January, and February, from the NE. and is a hot wind in some localities and a cold wind in others, according to circumstances."